Mátíù 10:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 “Nítorí náà, gbogbo ẹni tó bá fi hàn pé òun mọ̀ mí níwájú àwọn èèyàn,+ èmi náà máa fi hàn pé mo mọ̀ ọ́n níwájú Baba mi tó wà ní ọ̀run.+ 1 Kọ́ríńtì 15:58 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 58 Nítorí náà, ẹ̀yin ará mi ọ̀wọ́n, ẹ dúró gbọn-in,+ ẹ má yẹsẹ̀,* kí ẹ máa ní ohun púpọ̀ láti ṣe+ nínú iṣẹ́ Olúwa nígbà gbogbo, kí ẹ sì mọ̀ pé làálàá yín kò ní já sí asán+ nínú Olúwa.
32 “Nítorí náà, gbogbo ẹni tó bá fi hàn pé òun mọ̀ mí níwájú àwọn èèyàn,+ èmi náà máa fi hàn pé mo mọ̀ ọ́n níwájú Baba mi tó wà ní ọ̀run.+
58 Nítorí náà, ẹ̀yin ará mi ọ̀wọ́n, ẹ dúró gbọn-in,+ ẹ má yẹsẹ̀,* kí ẹ máa ní ohun púpọ̀ láti ṣe+ nínú iṣẹ́ Olúwa nígbà gbogbo, kí ẹ sì mọ̀ pé làálàá yín kò ní já sí asán+ nínú Olúwa.