Róòmù 8:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Ta ló máa fẹ̀sùn kan àwọn àyànfẹ́ Ọlọ́run? + Ọlọ́run ni Ẹni tó pè wọ́n ní olódodo.+ Éfésù 1:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 bí ó ṣe yàn wá láti wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú rẹ̀* ṣáájú ìgbà pípilẹ̀ ayé, kí a lè jẹ́ mímọ́, kí a sì wà láìní àbààwọ́n+ níwájú rẹ̀ nínú ìfẹ́. Kólósè 1:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 ẹ̀yin ló pa dà mú bá ara rẹ̀ rẹ́ báyìí nípasẹ̀ ẹran ara ẹni tó fi ara rẹ̀ lélẹ̀ fún ikú, kó lè mú yín wá síwájú rẹ̀ ní mímọ́ àti láìní àbààwọ́n àti láìní ẹ̀sùn kankan,+
4 bí ó ṣe yàn wá láti wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú rẹ̀* ṣáájú ìgbà pípilẹ̀ ayé, kí a lè jẹ́ mímọ́, kí a sì wà láìní àbààwọ́n+ níwájú rẹ̀ nínú ìfẹ́.
22 ẹ̀yin ló pa dà mú bá ara rẹ̀ rẹ́ báyìí nípasẹ̀ ẹran ara ẹni tó fi ara rẹ̀ lélẹ̀ fún ikú, kó lè mú yín wá síwájú rẹ̀ ní mímọ́ àti láìní àbààwọ́n àti láìní ẹ̀sùn kankan,+