Mátíù 24:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Nígbà náà, àmì Ọmọ èèyàn máa fara hàn ní ọ̀run, ìbànújẹ́ máa mú kí gbogbo àwọn ẹ̀yà tó wà ní ayé lu ara wọn,+ wọ́n sì máa rí Ọmọ èèyàn+ tó ń bọ̀ lórí àwọsánmà* ojú ọ̀run pẹ̀lú agbára àti ògo ńlá.+
30 Nígbà náà, àmì Ọmọ èèyàn máa fara hàn ní ọ̀run, ìbànújẹ́ máa mú kí gbogbo àwọn ẹ̀yà tó wà ní ayé lu ara wọn,+ wọ́n sì máa rí Ọmọ èèyàn+ tó ń bọ̀ lórí àwọsánmà* ojú ọ̀run pẹ̀lú agbára àti ògo ńlá.+