Ìfihàn 1:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Wò ó! Ó ń bọ̀ pẹ̀lú ìkùukùu,*+ gbogbo ojú sì máa rí i, títí kan àwọn tó gún un lọ́kọ̀; ìbànújẹ́ nítorí rẹ̀ sì máa mú kí gbogbo ẹ̀yà tó wà ní ayé lu ara wọn.+ Bẹ́ẹ̀ ni kó rí, Àmín.
7 Wò ó! Ó ń bọ̀ pẹ̀lú ìkùukùu,*+ gbogbo ojú sì máa rí i, títí kan àwọn tó gún un lọ́kọ̀; ìbànújẹ́ nítorí rẹ̀ sì máa mú kí gbogbo ẹ̀yà tó wà ní ayé lu ara wọn.+ Bẹ́ẹ̀ ni kó rí, Àmín.