Àìsáyà 48:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Fetí sí mi, ìwọ Jékọ́bù àti ìwọ Ísírẹ́lì, ẹni tí mo ti pè,Ẹnì kan náà ni mí.+ Èmi ni ẹni àkọ́kọ́; èmi náà ni ẹni ìkẹyìn.+ Ìfihàn 21:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ó sọ fún mi pé: “Wọ́n ti rí bẹ́ẹ̀! Èmi ni Ááfà àti Ómégà,* ìbẹ̀rẹ̀ àti òpin.+ Màá fún ẹnikẹ́ni tí òùngbẹ ń gbẹ ní omi látinú ìsun* omi ìyè lọ́fẹ̀ẹ́.*+ Ìfihàn 22:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Èmi ni Ááfà àti Ómégà,*+ ẹni àkọ́kọ́ àti ẹni ìkẹyìn, ìbẹ̀rẹ̀ àti òpin.
12 Fetí sí mi, ìwọ Jékọ́bù àti ìwọ Ísírẹ́lì, ẹni tí mo ti pè,Ẹnì kan náà ni mí.+ Èmi ni ẹni àkọ́kọ́; èmi náà ni ẹni ìkẹyìn.+
6 Ó sọ fún mi pé: “Wọ́n ti rí bẹ́ẹ̀! Èmi ni Ááfà àti Ómégà,* ìbẹ̀rẹ̀ àti òpin.+ Màá fún ẹnikẹ́ni tí òùngbẹ ń gbẹ ní omi látinú ìsun* omi ìyè lọ́fẹ̀ẹ́.*+