Ìfihàn 1:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Jèhófà* Ọlọ́run sọ pé, “Èmi ni Ááfà àti Ómégà,*+ Ẹni tó ti wà tipẹ́, tó wà báyìí, tó sì ń bọ̀, Olódùmarè.”+ Ìfihàn 22:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Èmi ni Ááfà àti Ómégà,*+ ẹni àkọ́kọ́ àti ẹni ìkẹyìn, ìbẹ̀rẹ̀ àti òpin.
8 Jèhófà* Ọlọ́run sọ pé, “Èmi ni Ááfà àti Ómégà,*+ Ẹni tó ti wà tipẹ́, tó wà báyìí, tó sì ń bọ̀, Olódùmarè.”+