6 Mo sì rí ọ̀dọ́ àgùntàn+ kan tó rí bí èyí tí wọ́n ti pa,+ ó dúró ní àárín ìtẹ́ náà àti àwọn ẹ̀dá alààyè mẹ́rin náà àti ní àárín àwọn àgbààgbà náà,+ ó ní ìwo méje àti ojú méje, àwọn ojú náà sì túmọ̀ sí ẹ̀mí méje ti Ọlọ́run+ tí a ti rán jáde sí gbogbo ayé.