Lúùkù 12:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 “Má bẹ̀rù, agbo kékeré,+ torí Baba yín ti fọwọ́ sí i láti fún yín ní Ìjọba náà.+