Hósíà 10:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Àwọn ibi gíga Bẹti-áfénì+ tó jẹ́ ẹ̀ṣẹ̀ Ísírẹ́lì,+ máa pa run pátápátá.+ Ẹ̀gún àti òṣùṣú yóò hù jáde lórí pẹpẹ wọn.+ Àwọn èèyàn yóò sọ fún àwọn òkè ńlá pé, ‘Ẹ bò wá mọ́lẹ̀!’ Wọ́n á sì sọ fún àwọn òkè kéékèèké pé, ‘Ẹ wó lù wá!’+ Lúùkù 23:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Wọ́n á wá bẹ̀rẹ̀ sí í sọ fún àwọn òkè ńláńlá pé, ‘Ẹ wó lù wá!’ àti fún àwọn òkè kéékèèké pé, ‘Ẹ bò wá mọ́lẹ̀!’+
8 Àwọn ibi gíga Bẹti-áfénì+ tó jẹ́ ẹ̀ṣẹ̀ Ísírẹ́lì,+ máa pa run pátápátá.+ Ẹ̀gún àti òṣùṣú yóò hù jáde lórí pẹpẹ wọn.+ Àwọn èèyàn yóò sọ fún àwọn òkè ńlá pé, ‘Ẹ bò wá mọ́lẹ̀!’ Wọ́n á sì sọ fún àwọn òkè kéékèèké pé, ‘Ẹ wó lù wá!’+
30 Wọ́n á wá bẹ̀rẹ̀ sí í sọ fún àwọn òkè ńláńlá pé, ‘Ẹ wó lù wá!’ àti fún àwọn òkè kéékèèké pé, ‘Ẹ bò wá mọ́lẹ̀!’+