Róòmù 8:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Nígbà náà, tí a bá jẹ́ ọmọ, ajogún ni wá pẹ̀lú, lóòótọ́ a jẹ́ ajogún Ọlọ́run, àmọ́ a jẹ́ ajùmọ̀jogún+ pẹ̀lú Kristi, kìkì tí a bá jọ jìyà,+ kí a lè ṣe wá lógo pẹ̀lú rẹ̀.+
17 Nígbà náà, tí a bá jẹ́ ọmọ, ajogún ni wá pẹ̀lú, lóòótọ́ a jẹ́ ajogún Ọlọ́run, àmọ́ a jẹ́ ajùmọ̀jogún+ pẹ̀lú Kristi, kìkì tí a bá jọ jìyà,+ kí a lè ṣe wá lógo pẹ̀lú rẹ̀.+