Ìfihàn 19:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ojú rẹ̀ jẹ́ ọwọ́ iná tó ń jó fòfò,+ adé dáyádémà* tó pọ̀ sì wà ní orí rẹ̀. Ó ní orúkọ kan tí a kọ, tí ẹnì kankan ò mọ̀ àfi òun fúnra rẹ̀,
12 Ojú rẹ̀ jẹ́ ọwọ́ iná tó ń jó fòfò,+ adé dáyádémà* tó pọ̀ sì wà ní orí rẹ̀. Ó ní orúkọ kan tí a kọ, tí ẹnì kankan ò mọ̀ àfi òun fúnra rẹ̀,