Ìfihàn 1:13, 14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 ẹnì kan tó dà bí ọmọ èèyàn+ wà láàárín àwọn ọ̀pá fìtílà náà, ó wọ aṣọ tó balẹ̀ dé ọrùn ẹsẹ̀, ó de ọ̀já wúrà mọ́ àyà rẹ̀. 14 Yàtọ̀ síyẹn, orí rẹ̀ àti irun rẹ̀ funfun bí ẹ̀gbọ̀n òwú, bíi yìnyín, ojú rẹ̀ sì dà bí ọwọ́ iná tó ń jó fòfò,+
13 ẹnì kan tó dà bí ọmọ èèyàn+ wà láàárín àwọn ọ̀pá fìtílà náà, ó wọ aṣọ tó balẹ̀ dé ọrùn ẹsẹ̀, ó de ọ̀já wúrà mọ́ àyà rẹ̀. 14 Yàtọ̀ síyẹn, orí rẹ̀ àti irun rẹ̀ funfun bí ẹ̀gbọ̀n òwú, bíi yìnyín, ojú rẹ̀ sì dà bí ọwọ́ iná tó ń jó fòfò,+