Jẹ́nẹ́sísì 3:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Màá mú kí ìwọ+ àti obìnrin+ náà di ọ̀tá+ ara yín,* ọmọ* rẹ+ àti ọmọ* rẹ̀+ yóò sì di ọ̀tá. Òun yóò fọ́ orí rẹ,*+ ìwọ yóò sì ṣe é léṣe* ní gìgísẹ̀.”+
15 Màá mú kí ìwọ+ àti obìnrin+ náà di ọ̀tá+ ara yín,* ọmọ* rẹ+ àti ọmọ* rẹ̀+ yóò sì di ọ̀tá. Òun yóò fọ́ orí rẹ,*+ ìwọ yóò sì ṣe é léṣe* ní gìgísẹ̀.”+