Jẹ́nẹ́sísì 22:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Gbogbo orílẹ̀-èdè tó wà láyé yóò gba ìbùkún fún ara wọn nípasẹ̀ ọmọ*+ rẹ torí pé o fetí sí ohùn+ mi.’” Jẹ́nẹ́sísì 49:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ọ̀pá àṣẹ kò ní kúrò lọ́dọ̀ Júdà,+ ọ̀pá aláṣẹ kò sì ní kúrò láàárín ẹsẹ̀ rẹ̀ títí Ṣílò* yóò fi dé,+ òun ni àwọn èèyàn yóò máa ṣègbọràn sí.+ Gálátíà 3:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Àwọn ìlérí náà la sọ fún Ábúráhámù àti fún ọmọ* rẹ̀.+ Kò sọ pé, “àti fún àwọn ọmọ* rẹ,” bíi pé wọ́n pọ̀. Kàkà bẹ́ẹ̀, ó sọ pé, “àti fún ọmọ* rẹ,” ìyẹn ẹnì kan ṣoṣo, tó jẹ́ Kristi.+ Gálátíà 3:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Yàtọ̀ síyẹn, bí ẹ bá jẹ́ ti Kristi, ẹ jẹ́ ọmọ* Ábúráhámù lóòótọ́,+ ajogún+ nípasẹ̀ ìlérí.+
18 Gbogbo orílẹ̀-èdè tó wà láyé yóò gba ìbùkún fún ara wọn nípasẹ̀ ọmọ*+ rẹ torí pé o fetí sí ohùn+ mi.’”
10 Ọ̀pá àṣẹ kò ní kúrò lọ́dọ̀ Júdà,+ ọ̀pá aláṣẹ kò sì ní kúrò láàárín ẹsẹ̀ rẹ̀ títí Ṣílò* yóò fi dé,+ òun ni àwọn èèyàn yóò máa ṣègbọràn sí.+
16 Àwọn ìlérí náà la sọ fún Ábúráhámù àti fún ọmọ* rẹ̀.+ Kò sọ pé, “àti fún àwọn ọmọ* rẹ,” bíi pé wọ́n pọ̀. Kàkà bẹ́ẹ̀, ó sọ pé, “àti fún ọmọ* rẹ,” ìyẹn ẹnì kan ṣoṣo, tó jẹ́ Kristi.+