Ìfihàn 12:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Àmọ́ a fún obìnrin náà ní ìyẹ́ méjèèjì ẹyẹ idì ńlá,+ kó lè fò lọ sí àyè rẹ̀ nínú aginjù, níbi tí wọ́n á ti máa bọ́ ọ fún àkókò kan àti àwọn àkókò àti ààbọ̀ àkókò*+ níbi tí ojú ejò náà+ ò tó.
14 Àmọ́ a fún obìnrin náà ní ìyẹ́ méjèèjì ẹyẹ idì ńlá,+ kó lè fò lọ sí àyè rẹ̀ nínú aginjù, níbi tí wọ́n á ti máa bọ́ ọ fún àkókò kan àti àwọn àkókò àti ààbọ̀ àkókò*+ níbi tí ojú ejò náà+ ò tó.