Ìfihàn 12:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Obìnrin náà sá lọ sí aginjù, níbi tí Ọlọ́run pèsè àyè sílẹ̀ sí fún un, ibẹ̀ ni wọ́n ti máa bọ́ ọ fún ọ̀tàlélẹ́gbẹ̀fà (1,260) ọjọ́.+
6 Obìnrin náà sá lọ sí aginjù, níbi tí Ọlọ́run pèsè àyè sílẹ̀ sí fún un, ibẹ̀ ni wọ́n ti máa bọ́ ọ fún ọ̀tàlélẹ́gbẹ̀fà (1,260) ọjọ́.+