Jẹ́nẹ́sísì 3:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Màá mú kí ìwọ+ àti obìnrin+ náà di ọ̀tá+ ara yín,* ọmọ* rẹ+ àti ọmọ* rẹ̀+ yóò sì di ọ̀tá. Òun yóò fọ́ orí rẹ,*+ ìwọ yóò sì ṣe é léṣe* ní gìgísẹ̀.”+ Ìfihàn 12:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Lẹ́yìn náà, mo rí àmì ńlá kan ní ọ̀run: Wọ́n fi oòrùn ṣe obìnrin kan+ lọ́ṣọ̀ọ́,* òṣùpá wà lábẹ́ ẹsẹ̀ rẹ̀, adé oníràwọ̀ méjìlá (12) sì wà ní orí rẹ̀,
15 Màá mú kí ìwọ+ àti obìnrin+ náà di ọ̀tá+ ara yín,* ọmọ* rẹ+ àti ọmọ* rẹ̀+ yóò sì di ọ̀tá. Òun yóò fọ́ orí rẹ,*+ ìwọ yóò sì ṣe é léṣe* ní gìgísẹ̀.”+
12 Lẹ́yìn náà, mo rí àmì ńlá kan ní ọ̀run: Wọ́n fi oòrùn ṣe obìnrin kan+ lọ́ṣọ̀ọ́,* òṣùpá wà lábẹ́ ẹsẹ̀ rẹ̀, adé oníràwọ̀ méjìlá (12) sì wà ní orí rẹ̀,