Ìfihàn 3:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 “‘Màá fi ẹni tó bá ṣẹ́gun ṣe òpó nínú tẹ́ńpìlì Ọlọ́run mi, kò ní jáde kúrò nínú rẹ̀ mọ́, màá sì kọ orúkọ Ọlọ́run mi sára rẹ̀ + àti orúkọ ìlú Ọlọ́run mi, Jerúsálẹ́mù Tuntun+ tó ń sọ̀ kalẹ̀ bọ̀ láti ọ̀run látọ̀dọ̀ Ọlọ́run mi àti orúkọ mi tuntun.+
12 “‘Màá fi ẹni tó bá ṣẹ́gun ṣe òpó nínú tẹ́ńpìlì Ọlọ́run mi, kò ní jáde kúrò nínú rẹ̀ mọ́, màá sì kọ orúkọ Ọlọ́run mi sára rẹ̀ + àti orúkọ ìlú Ọlọ́run mi, Jerúsálẹ́mù Tuntun+ tó ń sọ̀ kalẹ̀ bọ̀ láti ọ̀run látọ̀dọ̀ Ọlọ́run mi àti orúkọ mi tuntun.+