Àìsáyà 21:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Wo ohun tó ń bọ̀: Àwọn ọkùnrin wà nínú kẹ̀kẹ́ ogun tí wọ́n so àwọn ẹṣin mọ́!”+ Ó wá sọ pé: “Ó ti ṣubú! Bábílónì ti ṣubú!+ Gbogbo ère gbígbẹ́ àwọn ọlọ́run rẹ̀ ló ti fọ́ sílẹ̀ túútúú!”+ Ìfihàn 18:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Áńgẹ́lì kan tó lágbára wá gbé òkúta kan tó dà bí ọlọ ńlá sókè, ó sì jù ú sínú òkun, ó ní: “Báyìí la ṣe máa yára ju Bábílónì ìlú ńlá náà sísàlẹ̀, a ò sì ní rí i mọ́ láé.+
9 Wo ohun tó ń bọ̀: Àwọn ọkùnrin wà nínú kẹ̀kẹ́ ogun tí wọ́n so àwọn ẹṣin mọ́!”+ Ó wá sọ pé: “Ó ti ṣubú! Bábílónì ti ṣubú!+ Gbogbo ère gbígbẹ́ àwọn ọlọ́run rẹ̀ ló ti fọ́ sílẹ̀ túútúú!”+
21 Áńgẹ́lì kan tó lágbára wá gbé òkúta kan tó dà bí ọlọ ńlá sókè, ó sì jù ú sínú òkun, ó ní: “Báyìí la ṣe máa yára ju Bábílónì ìlú ńlá náà sísàlẹ̀, a ò sì ní rí i mọ́ láé.+