Mátíù 16:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Bákan náà, mò ń sọ fún ọ pé: Ìwọ ni Pétérù,+ orí àpáta yìí+ sì ni màá kọ́ ìjọ mi sí, àwọn ibodè Isà Òkú* kò sì ní borí rẹ̀. Jòhánù 6:54 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 54 Ẹnikẹ́ni tó bá ń jẹ ẹran ara mi, tó sì ń mu ẹ̀jẹ̀ mi máa ní ìyè àìnípẹ̀kun, màá sì jí i dìde+ ní ọjọ́ ìkẹyìn; Jòhánù 11:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Jésù sọ fún un pé: “Èmi ni àjíǹde àti ìyè.+ Ẹni tó bá ní ìgbàgbọ́ nínú mi, tó bá tiẹ̀ kú, ó máa yè;
18 Bákan náà, mò ń sọ fún ọ pé: Ìwọ ni Pétérù,+ orí àpáta yìí+ sì ni màá kọ́ ìjọ mi sí, àwọn ibodè Isà Òkú* kò sì ní borí rẹ̀.
54 Ẹnikẹ́ni tó bá ń jẹ ẹran ara mi, tó sì ń mu ẹ̀jẹ̀ mi máa ní ìyè àìnípẹ̀kun, màá sì jí i dìde+ ní ọjọ́ ìkẹyìn;
25 Jésù sọ fún un pé: “Èmi ni àjíǹde àti ìyè.+ Ẹni tó bá ní ìgbàgbọ́ nínú mi, tó bá tiẹ̀ kú, ó máa yè;