-
Ìṣe 7:44Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
44 “Àwọn baba ńlá wa ní àgọ́ ẹ̀rí nínú aginjù, bí Ọlọ́run ṣe pa á láṣẹ nígbà tó sọ fún Mósè pé kó ṣe é bí èyí tí ó rí.+
-
-
Hébérù 9:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Àmọ́, nígbà tí Kristi dé bí àlùfáà àgbà àwọn ohun rere tó ti ṣẹlẹ̀, ó gba inú àgọ́ tó tóbi jù, tó sì jẹ́ pípé jù, tí wọn ò fi ọwọ́ ṣe, ìyẹn tí kì í ṣe ti ẹ̀dá yìí.
-