Jeremáyà 51:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 “Ìwọ obìnrin tó ń gbé lórí omi púpọ̀,+Tí o ní ìṣúra tó pọ̀ rẹpẹtẹ,+Òpin rẹ ti dé, o ti dé òpin* èrè tí ò ń jẹ.+ Ìfihàn 17:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ó sọ fún mi pé: “Àwọn omi tí o rí, níbi tí aṣẹ́wó náà jókòó sí, túmọ̀ sí àwọn èèyàn àti èrò rẹpẹtẹ àti àwọn orílẹ̀-èdè àti àwọn ahọ́n.*+ Ìfihàn 19:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 torí òótọ́ àti òdodo ni àwọn ìdájọ́ rẹ̀.+ Torí ó ti ṣèdájọ́ aṣẹ́wó ńlá tó fi ìṣekúṣe* rẹ̀ ba ayé jẹ́, ó sì ti gbẹ̀san ẹ̀jẹ̀ àwọn ẹrú rẹ̀ tó wà lọ́wọ́ rẹ̀.”*+
13 “Ìwọ obìnrin tó ń gbé lórí omi púpọ̀,+Tí o ní ìṣúra tó pọ̀ rẹpẹtẹ,+Òpin rẹ ti dé, o ti dé òpin* èrè tí ò ń jẹ.+
15 Ó sọ fún mi pé: “Àwọn omi tí o rí, níbi tí aṣẹ́wó náà jókòó sí, túmọ̀ sí àwọn èèyàn àti èrò rẹpẹtẹ àti àwọn orílẹ̀-èdè àti àwọn ahọ́n.*+
2 torí òótọ́ àti òdodo ni àwọn ìdájọ́ rẹ̀.+ Torí ó ti ṣèdájọ́ aṣẹ́wó ńlá tó fi ìṣekúṣe* rẹ̀ ba ayé jẹ́, ó sì ti gbẹ̀san ẹ̀jẹ̀ àwọn ẹrú rẹ̀ tó wà lọ́wọ́ rẹ̀.”*+