ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 32:43
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  43 Ẹ bá àwọn èèyàn+ rẹ̀ yọ̀, ẹ̀yin orílẹ̀-èdè,

      Torí ó máa gbẹ̀san ẹ̀jẹ̀ àwọn ìránṣẹ́+ rẹ̀,

      Ó máa san àwọn ọ̀tá+ rẹ̀ lẹ́san,

      Ó sì máa ṣe ètùtù fún ilẹ̀ àwọn èèyàn rẹ̀.”*

  • 2 Àwọn Ọba 9:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Kí o pa àwọn ará ilé Áhábù olúwa rẹ, màá sì gbẹ̀san ẹ̀jẹ̀ àwọn ìránṣẹ́ mi wòlíì àti ti gbogbo ìránṣẹ́ Jèhófà tí Jésíbẹ́lì pa.+

  • Sáàmù 79:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Kí nìdí tí àwọn orílẹ̀-èdè á fi sọ pé: “Ọlọ́run wọn dà?”+

      Níṣojú wa, jẹ́ kí àwọn orílẹ̀-èdè mọ̀ pé

      O ti gbẹ̀san ẹ̀jẹ̀ àwọn ìránṣẹ́ rẹ tí wọ́n ta sílẹ̀.+

  • Ìfihàn 18:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 “Máa yọ̀ nítorí rẹ̀, ìwọ ọ̀run+ àti ẹ̀yin ẹni mímọ́,+ ẹ̀yin àpọ́sítélì àti wòlíì, torí pé Ọlọ́run ti kéde ìdájọ́ sórí rẹ̀ nítorí yín!”+

  • Ìfihàn 18:24
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 24 Àní inú rẹ̀ ni a ti rí ẹ̀jẹ̀ àwọn wòlíì àti ti àwọn ẹni mímọ́+ àti ti gbogbo àwọn tí wọ́n pa ní ayé.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́