Sáàmù 75:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ife kan wà ní ọwọ́ Jèhófà;+Wáìnì inú rẹ̀ ń ru, wọ́n sì pò ó pọ̀ dáadáa. Ó dájú pé yóò dà á jáde,Gbogbo àwọn ẹni burúkú ayé yóò mu ún tòun ti gẹ̀dẹ̀gẹ́dẹ̀ rẹ̀.”+
8 Ife kan wà ní ọwọ́ Jèhófà;+Wáìnì inú rẹ̀ ń ru, wọ́n sì pò ó pọ̀ dáadáa. Ó dájú pé yóò dà á jáde,Gbogbo àwọn ẹni burúkú ayé yóò mu ún tòun ti gẹ̀dẹ̀gẹ́dẹ̀ rẹ̀.”+