Àìsáyà 34:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 A ò ní pa á, ní òru tàbí ní ọ̀sán;Èéfín rẹ̀ á máa ròkè títí láé. Ibi ìparun ló máa jẹ́ láti ìran dé ìran;Kò sẹ́ni tó máa gba ibẹ̀ kọjá títí láé àti láéláé.+
10 A ò ní pa á, ní òru tàbí ní ọ̀sán;Èéfín rẹ̀ á máa ròkè títí láé. Ibi ìparun ló máa jẹ́ láti ìran dé ìran;Kò sẹ́ni tó máa gba ibẹ̀ kọjá títí láé àti láéláé.+