Ìfihàn 4:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ohun kan tó rí bí òkun tó ń dán bíi gíláàsì+ wà níwájú ìtẹ́ náà, ó dà bíi kírísítálì. Ẹ̀dá alààyè mẹ́rin+ tí ojú kún iwájú àti ẹ̀yìn wọn wà ní àárín ìtẹ́ náà* àti yí ká ìtẹ́ náà.
6 Ohun kan tó rí bí òkun tó ń dán bíi gíláàsì+ wà níwájú ìtẹ́ náà, ó dà bíi kírísítálì. Ẹ̀dá alààyè mẹ́rin+ tí ojú kún iwájú àti ẹ̀yìn wọn wà ní àárín ìtẹ́ náà* àti yí ká ìtẹ́ náà.