Dáníẹ́lì 7:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Àmọ́ àwọn ẹni mímọ́ ti Onípò Àjùlọ+ máa gba ìjọba,+ ìjọba náà sì máa jẹ́ tiwọn+ títí láé, àní títí láé àti láéláé.’ Ìfihàn 3:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Màá jẹ́ kí ẹni tó bá ṣẹ́gun+ jókòó pẹ̀lú mi lórí ìtẹ́ mi,+ bí èmi náà ṣe ṣẹ́gun, tí mo sì jókòó+ pẹ̀lú Baba mi lórí ìtẹ́ rẹ̀.
18 Àmọ́ àwọn ẹni mímọ́ ti Onípò Àjùlọ+ máa gba ìjọba,+ ìjọba náà sì máa jẹ́ tiwọn+ títí láé, àní títí láé àti láéláé.’
21 Màá jẹ́ kí ẹni tó bá ṣẹ́gun+ jókòó pẹ̀lú mi lórí ìtẹ́ mi,+ bí èmi náà ṣe ṣẹ́gun, tí mo sì jókòó+ pẹ̀lú Baba mi lórí ìtẹ́ rẹ̀.