Sáàmù 89:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Èmi yóò fi í ṣe àkọ́bí,+Ẹni tó ga jù lọ nínú àwọn ọba ayé.+ 1 Tímótì 6:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 èyí tí ẹni tó jẹ́ aláyọ̀ àti Ọba Alágbára Gíga kan ṣoṣo máa fi hàn nígbà tí àwọn àkókò rẹ̀ bá tó. Òun ni Ọba àwọn ọba àti Olúwa àwọn olúwa,+ Ìfihàn 19:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Orúkọ kan wà tí a kọ sára aṣọ àwọ̀lékè rẹ̀, àní sórí itan rẹ̀, ìyẹn Ọba àwọn ọba àti Olúwa àwọn olúwa.+
15 èyí tí ẹni tó jẹ́ aláyọ̀ àti Ọba Alágbára Gíga kan ṣoṣo máa fi hàn nígbà tí àwọn àkókò rẹ̀ bá tó. Òun ni Ọba àwọn ọba àti Olúwa àwọn olúwa,+
16 Orúkọ kan wà tí a kọ sára aṣọ àwọ̀lékè rẹ̀, àní sórí itan rẹ̀, ìyẹn Ọba àwọn ọba àti Olúwa àwọn olúwa.+