1 Tímótì 6:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 èyí tí ẹni tó jẹ́ aláyọ̀ àti Ọba Alágbára Gíga kan ṣoṣo máa fi hàn nígbà tí àwọn àkókò rẹ̀ bá tó. Òun ni Ọba àwọn ọba àti Olúwa àwọn olúwa,+ Ìfihàn 1:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 àti látọ̀dọ̀ Jésù Kristi, “Ẹlẹ́rìí Olóòótọ́,”+ “àkọ́bí nínú àwọn òkú,”+ àti “Alákòóso àwọn ọba ayé.”+ Ẹni tó nífẹ̀ẹ́ wa,+ tó fi ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ dá wa sílẹ̀ nínú àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa+— Ìfihàn 19:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Orúkọ kan wà tí a kọ sára aṣọ àwọ̀lékè rẹ̀, àní sórí itan rẹ̀, ìyẹn Ọba àwọn ọba àti Olúwa àwọn olúwa.+
15 èyí tí ẹni tó jẹ́ aláyọ̀ àti Ọba Alágbára Gíga kan ṣoṣo máa fi hàn nígbà tí àwọn àkókò rẹ̀ bá tó. Òun ni Ọba àwọn ọba àti Olúwa àwọn olúwa,+
5 àti látọ̀dọ̀ Jésù Kristi, “Ẹlẹ́rìí Olóòótọ́,”+ “àkọ́bí nínú àwọn òkú,”+ àti “Alákòóso àwọn ọba ayé.”+ Ẹni tó nífẹ̀ẹ́ wa,+ tó fi ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ dá wa sílẹ̀ nínú àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa+—
16 Orúkọ kan wà tí a kọ sára aṣọ àwọ̀lékè rẹ̀, àní sórí itan rẹ̀, ìyẹn Ọba àwọn ọba àti Olúwa àwọn olúwa.+