ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 20
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Àìsáyà

      • Àmì àti àpẹẹrẹ ohun tó máa ṣẹlẹ̀ sí Íjíbítì àti Etiópíà (1-6)

Àìsáyà 20:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ọ̀gágun.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joṣ 13:2, 3
  • +Emọ 1:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    5/1/2015, ojú ìwé 9

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 210-211

Àìsáyà 20:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “aṣọ àpò ìdọ̀họ.”

  • *

    Tàbí “pẹ̀lú aṣọ jáńpé lára.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 1:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/1/2006, ojú ìwé 11

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 211

Àìsáyà 20:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 8:18
  • +Ais 19:1
  • +Ais 18:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 211-212

Àìsáyà 20:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ojú máa ti Íjíbítì.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 19:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 211-212

Àìsáyà 20:5

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “tí ẹwà rẹ̀ wù wọ́n.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 212-213

Àìsáyà 20:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 212-213

Àwọn míì

Àìsá. 20:1Joṣ 13:2, 3
Àìsá. 20:1Emọ 1:8
Àìsá. 20:2Ais 1:1
Àìsá. 20:3Ais 8:18
Àìsá. 20:3Ais 19:1
Àìsá. 20:3Ais 18:1
Àìsá. 20:4Ais 19:4
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Àìsáyà 20:1-6

Àìsáyà

20 Ní ọdún tí Ságónì ọba Ásíríà rán Tátánì* lọ sí Áṣídódì,+ ó bá Áṣídódì jagun, ó sì gbà á.+ 2 Ní àkókò yẹn, Jèhófà gbẹnu Àìsáyà+ ọmọ Émọ́ọ̀sì sọ̀rọ̀, ó ní: “Lọ, kí o tú aṣọ ọ̀fọ̀* kúrò ní ìbàdí rẹ, kí o sì bọ́ bàtà kúrò ní ẹsẹ̀ rẹ.” Ó sì ṣe bẹ́ẹ̀, ó wá ń rìn káàkiri ní ìhòòhò* àti láìwọ bàtà.

3 Jèhófà wá sọ pé: “Bí ìránṣẹ́ mi Àìsáyà ṣe rìn káàkiri ní ìhòòhò, láìwọ bàtà fún ọdún mẹ́ta, láti fi ṣe àmì+ àti àpẹẹrẹ ohun tó máa ṣẹlẹ̀ sí Íjíbítì+ àti Etiópíà,+ 4 bẹ́ẹ̀ gẹ́lẹ́ ni ọba Ásíríà máa kó àwọn ẹrú Íjíbítì+ àti Etiópíà lọ sí ìgbèkùn, àwọn ọmọdékùnrin àtàwọn àgbà ọkùnrin, ní ìhòòhò àti láìwọ bàtà, ìdí wọn á sì hàn síta, Íjíbítì máa rin ìhòòhò.* 5 Ẹ̀rù máa bà wọ́n, ojú sì máa tì wọ́n torí Etiópíà tí wọ́n gbẹ́kẹ̀ lé àti Íjíbítì tí wọ́n fi ń yangàn.* 6 Ní ọjọ́ yẹn, àwọn tó ń gbé ilẹ̀ etíkun yìí máa sọ pé, ‘Ẹ wo ohun tó ṣẹlẹ̀ sí ẹni tí a gbẹ́kẹ̀ lé, tí a sá lọ bá pé kó ràn wá lọ́wọ́, kó sì gbà wá lọ́wọ́ ọba Ásíríà! Báwo la ṣe máa yè bọ́ báyìí?’”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́