ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Àwọn Ọba 22
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 2 Àwọn Ọba

      • Jòsáyà di ọba Júdà (1, 2)

      • Bí wọ́n ṣe máa tún tẹ́ńpìlì ṣe (3-7)

      • Wọ́n rí ìwé Òfin (8-13)

      • Húlídà sọ tẹ́lẹ̀ pé àjálù máa ṣẹlẹ̀ (14-20)

2 Àwọn Ọba 22:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 13:2; Jer 1:2; Sef 1:1
  • +2Kr 34:1, 2
  • +Joṣ 15:20, 39

2 Àwọn Ọba 22:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 15:5

2 Àwọn Ọba 22:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 34:8

2 Àwọn Ọba 22:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kr 6:13
  • +2Ọb 12:4, 5; 2Kr 24:8
  • +2Ọb 12:9; 2Kr 34:9

2 Àwọn Ọba 22:5

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “tó sán.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 12:11, 12; 2Kr 34:10

2 Àwọn Ọba 22:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 34:11

2 Àwọn Ọba 22:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 12:15; 2Kr 34:12

2 Àwọn Ọba 22:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 22:3
  • +Di 31:24-26
  • +2Kr 34:14, 15

2 Àwọn Ọba 22:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “da owó tí wọ́n rí nínú ilé náà jáde.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 34:16-18

2 Àwọn Ọba 22:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 31:9

2 Àwọn Ọba 22:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 34:19-21; Joẹ 2:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/1/2000, ojú ìwé 30

2 Àwọn Ọba 22:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 25:22; Jer 26:24

2 Àwọn Ọba 22:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 4:24; 29:27; 31:17

2 Àwọn Ọba 22:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 15:20; Ond 4:4; Ne 6:14; Lk 2:36; Iṣe 21:8, 9
  • +2Kr 34:22-28

2 Àwọn Ọba 22:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 22:8

2 Àwọn Ọba 22:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 20:3; Di 32:17; Ond 2:12; Jer 2:11
  • +Ais 2:8
  • +Di 32:22; Ais 33:14; Jer 7:20; Isk 20:48

2 Àwọn Ọba 22:19

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “ọkàn rẹ rọ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 21:29; Jem 4:6
  • +2Ọb 22:11

2 Àwọn Ọba 22:20

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Àkànlò èdè yìí ni wọ́n fi ń sọ pé èèyàn kú.

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/2000, ojú ìwé 30

    9/15/2000, ojú ìwé 30

Àwọn míì

2 Ọba 22:11Ọb 13:2; Jer 1:2; Sef 1:1
2 Ọba 22:12Kr 34:1, 2
2 Ọba 22:1Joṣ 15:20, 39
2 Ọba 22:21Ọb 15:5
2 Ọba 22:32Kr 34:8
2 Ọba 22:41Kr 6:13
2 Ọba 22:42Ọb 12:4, 5; 2Kr 24:8
2 Ọba 22:42Ọb 12:9; 2Kr 34:9
2 Ọba 22:52Ọb 12:11, 12; 2Kr 34:10
2 Ọba 22:62Kr 34:11
2 Ọba 22:72Ọb 12:15; 2Kr 34:12
2 Ọba 22:82Ọb 22:3
2 Ọba 22:8Di 31:24-26
2 Ọba 22:82Kr 34:14, 15
2 Ọba 22:92Kr 34:16-18
2 Ọba 22:10Di 31:9
2 Ọba 22:112Kr 34:19-21; Joẹ 2:13
2 Ọba 22:122Ọb 25:22; Jer 26:24
2 Ọba 22:13Di 4:24; 29:27; 31:17
2 Ọba 22:14Ẹk 15:20; Ond 4:4; Ne 6:14; Lk 2:36; Iṣe 21:8, 9
2 Ọba 22:142Kr 34:22-28
2 Ọba 22:162Ọb 22:8
2 Ọba 22:17Ẹk 20:3; Di 32:17; Ond 2:12; Jer 2:11
2 Ọba 22:17Ais 2:8
2 Ọba 22:17Di 32:22; Ais 33:14; Jer 7:20; Isk 20:48
2 Ọba 22:191Ọb 21:29; Jem 4:6
2 Ọba 22:192Ọb 22:11
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
2 Àwọn Ọba 22:1-20

Àwọn Ọba Kejì

22 Ọmọ ọdún mẹ́jọ ni Jòsáyà+ nígbà tó jọba, ọdún mọ́kànlélọ́gbọ̀n (31) ló sì fi ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù.+ Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Jédídà ọmọ Ádáyà láti Bósíkátì.+ 2 Ó ṣe ohun tí ó tọ́ ní ojú Jèhófà, ó rìn ní gbogbo ọ̀nà Dáfídì baba ńlá rẹ̀,+ kò sì yà sí ọ̀tún tàbí sí òsì.

3 Ní ọdún kejìdínlógún Ọba Jòsáyà, ọba rán Ṣáfánì akọ̀wé tó jẹ́ ọmọ Asaláyà ọmọ Méṣúlámù sí ilé Jèhófà,+ ó ní: 4 “Lọ bá Hilikáyà+ àlùfáà àgbà, ní kó gba gbogbo owó tí wọ́n mú wá sí ilé Jèhófà+ jọ, èyí tí àwọn aṣọ́nà gbà lọ́wọ́ àwọn èèyàn náà.+ 5 Ní kí wọ́n kó o fún àwọn tí wọ́n yàn láti máa bójú tó iṣẹ́ ilé Jèhófà, àwọn yìí ló máa fún àwọn tó ń ṣiṣẹ́ nínú ilé Jèhófà láti tún àwọn ibi tó bà jẹ́* lára ilé náà ṣe,+ 6 ìyẹn àwọn oníṣẹ́ ọnà àti àwọn kọ́lékọ́lé àti àwọn mọlémọlé; owó yìí ni kí wọ́n fi ra àwọn ẹ̀là gẹdú àti àwọn òkúta gbígbẹ́ tí wọ́n á fi tún ilé náà ṣe.+ 7 Àmọ́, a ò ní sọ pé kí wọ́n ṣe ìṣírò owó tí wọ́n fún wọn, torí pé wọ́n ṣeé fọkàn tán.”+

8 Lẹ́yìn náà, Hilikáyà àlùfáà àgbà sọ fún Ṣáfánì akọ̀wé+ pé: “Mo ti rí ìwé Òfin+ ní ilé Jèhófà.” Torí náà, Hilikáyà fún Ṣáfánì ní ìwé náà, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í kà á.+ 9 Lẹ́yìn náà, Ṣáfánì akọ̀wé lọ sọ́dọ̀ ọba, ó sì sọ fún un pé: “Àwọn ìránṣẹ́ rẹ ti kó owó tí wọ́n rí nínú ilé náà,* wọ́n sì ti kó o fún àwọn tí wọ́n yàn láti máa bójú tó iṣẹ́ ilé Jèhófà.”+ 10 Ṣáfánì akọ̀wé tún sọ fún ọba pé: “Ìwé kan+ wà tí àlùfáà Hilikáyà fún mi.” Ṣáfánì sì bẹ̀rẹ̀ sí í kà á níwájú ọba.

11 Gbàrà tí ọba gbọ́ àwọn ọ̀rọ̀ inú ìwé Òfin náà, ó fa aṣọ rẹ̀ ya.+ 12 Ọba wá pa àṣẹ yìí fún àlùfáà Hilikáyà, Áhíkámù+ ọmọ Ṣáfánì, Ákíbórì ọmọ Mikáyà, Ṣáfánì akọ̀wé àti Ásáyà ìránṣẹ́ ọba pé: 13 “Ẹ lọ wádìí lọ́dọ̀ Jèhófà nítorí tèmi àti nítorí àwọn èèyàn yìí àti nítorí gbogbo Júdà nípa àwọn ọ̀rọ̀ inú ìwé tí a rí yìí; torí ìbínú Jèhófà tó ń jó bí iná lórí wa kò kéré,+ nítorí àwọn baba ńlá wa kò tẹ̀ lé àwọn ọ̀rọ̀ inú ìwé yìí láti ṣe gbogbo ohun tó wà lákọsílẹ̀ fún wa.”

14 Torí náà, àlùfáà Hilikáyà, Áhíkámù, Ákíbórì, Ṣáfánì àti Ásáyà lọ sọ́dọ̀ wòlíì obìnrin+ tó ń jẹ́ Húlídà. Òun ni ìyàwó Ṣálúmù ọmọ Tíkífà ọmọ Háhásì, ẹni tó ń bójú tó ibi tí wọ́n ń kó aṣọ sí. Ó ń gbé ní Apá Kejì Jerúsálẹ́mù; wọ́n sì bá a sọ̀rọ̀ níbẹ̀.+ 15 Ó sọ fún wọn pé: “Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì sọ nìyí, ‘Ẹ sọ fún ọkùnrin tó rán yín wá sọ́dọ̀ mi pé: 16 “Ohun tí Jèhófà sọ nìyí, ‘Màá mú àjálù bá ibí yìí àti àwọn tó ń gbé ibẹ̀, gbogbo ohun tó wà nínú ìwé tí ọba Júdà kà ni màá ṣe.+ 17 Nítorí pé wọ́n ti fi mí sílẹ̀, wọ́n sì ń mú ẹbọ rú èéfín sí àwọn ọlọ́run míì+ láti fi gbogbo iṣẹ́ ọwọ́ wọn mú mi bínú,+ ìbínú mi máa bẹ̀rẹ̀ sí í jó bí iná lórí ibí yìí, kò sì ní ṣeé pa.’”+ 18 Àmọ́, ní ti ọba Júdà tó rán yín pé kí ẹ lọ wádìí lọ́dọ̀ Jèhófà, ẹ sọ fún un pé, “Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì sọ nìyí: ‘Ní ti àwọn ọ̀rọ̀ tí o gbọ́, 19 nítorí pé ọlọ́kàn tútù ni ọ́* tí o sì rẹ ara rẹ sílẹ̀+ níwájú Jèhófà bí o ṣe gbọ́ ohun tí mo sọ pé màá ṣe sí ibí yìí àti sí àwọn tó ń gbé ibẹ̀, pé wọ́n á di ohun àríbẹ̀rù àti ẹni ègún, tí o sì fa aṣọ rẹ ya,+ tí ò ń sunkún níwájú mi, èmi náà ti gbọ́ ohun tí o sọ, ni Jèhófà wí. 20 Ìdí nìyẹn tí màá fi kó ọ jọ sọ́dọ̀ àwọn baba ńlá rẹ,* a ó tẹ́ ọ sínú sàréè rẹ ní àlàáfíà, ojú rẹ ò ní rí gbogbo àjálù tí màá mú bá ibí yìí.’”’” Lẹ́yìn náà, wọ́n mú èsì náà wá fún ọba.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́