ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 39
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Àìsáyà

      • Àwọn ìránṣẹ́ láti Bábílónì (1-8)

Àìsáyà 39:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 32:23
  • +2Ọb 20:5, 12, 13

Àìsáyà 39:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “yọ̀ nítorí wọn.”

  • *

    Tàbí “ààfin.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 32:27

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 396-397

Àìsáyà 39:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 20:14, 15

Àìsáyà 39:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ààfin.”

  • *

    Tàbí “ààfin.”

Àìsáyà 39:6

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ààfin.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 24:11, 13; 25:13; 2Kr 36:18; Da 1:1, 2
  • +2Ọb 20:16-18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 396-397

Àìsáyà 39:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 24:12; Da 2:49; 5:29

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 396-397

Àìsáyà 39:8

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “òtítọ́.”

  • *

    Ní Héb., “ní àwọn ọjọ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 20:19

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 397

Àwọn míì

Àìsá. 39:12Kr 32:23
Àìsá. 39:12Ọb 20:5, 12, 13
Àìsá. 39:22Kr 32:27
Àìsá. 39:32Ọb 20:14, 15
Àìsá. 39:62Ọb 24:11, 13; 25:13; 2Kr 36:18; Da 1:1, 2
Àìsá. 39:62Ọb 20:16-18
Àìsá. 39:72Ọb 24:12; Da 2:49; 5:29
Àìsá. 39:82Ọb 20:19
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Àìsáyà 39:1-8

Àìsáyà

39 Ní àkókò yẹn, ọba Bábílónì, ìyẹn Merodaki-báládánì ọmọ Báládánì, fi àwọn lẹ́tà àti ẹ̀bùn ránṣẹ́ sí Hẹsikáyà,+ torí ó gbọ́ pé Hẹsikáyà ṣàìsàn, ara rẹ̀ sì ti yá.+ 2 Hẹsikáyà kí wọn káàbọ̀ tayọ̀tayọ̀,* ó sì fi ohun tó wà nínú ilé ìṣúra rẹ̀ hàn wọ́n,+ ìyẹn fàdákà, wúrà, òróró básámù àti àwọn òróró míì tó ṣeyebíye, pẹ̀lú gbogbo ilé tó ń kó ohun ìjà sí àti gbogbo ohun tó wà nínú àwọn ibi ìṣúra rẹ̀. Kò sí nǹkan tí Hẹsikáyà kò fi hàn wọ́n nínú ilé* rẹ̀ àti ní gbogbo agbègbè tó wà lábẹ́ àkóso rẹ̀.

3 Lẹ́yìn náà, wòlíì Àìsáyà wá sọ́dọ̀ Ọba Hẹsikáyà, ó sì béèrè lọ́wọ́ rẹ̀ pé: “Kí ni àwọn ọkùnrin yìí sọ, ibo ni wọ́n sì ti wá?” Torí náà, Hẹsikáyà sọ pé: “Ibi tó jìnnà ni wọ́n ti wá, láti Bábílónì.”+ 4 Ó tún béèrè pé: “Kí ni wọ́n rí nínú ilé* rẹ?” Hẹsikáyà fèsì pé: “Gbogbo ohun tó wà nínú ilé* mi ni wọ́n rí. Kò sí nǹkan kan tó wà nínú àwọn ibi ìṣúra mi tí mi ò fi hàn wọ́n.”

5 Àìsáyà wá sọ fún Hẹsikáyà pé: “Gbọ́ ọ̀rọ̀ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, 6 ‘Wò ó! Ọjọ́ ń bọ̀ tí wọ́n máa kó gbogbo ohun tó wà nínú ilé* rẹ àti gbogbo ohun tí àwọn baba ńlá rẹ ti kó jọ títí di òní yìí lọ sí Bábílónì. Kò ní ku nǹkan kan,’+ ni Jèhófà wí.+ 7 ‘Wọ́n á mú àwọn kan lára àwọn ọmọ tí o máa bí, wọ́n á sì di òṣìṣẹ́ ààfin ní ààfin ọba Bábílónì.’”+

8 Ni Hẹsikáyà bá sọ fún Àìsáyà pé: “Ọ̀rọ̀ Jèhófà tí o sọ dáa.” Ó wá fi kún un pé: “Torí àlàáfíà àti ìfọkànbalẹ̀* máa wà lásìkò* tèmi.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́