ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 11
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Jẹ́nẹ́sísì

      • Ilé Gogoro Bábélì (1-4)

      • Jèhófà da èdè rú (5-9)

      • Látorí Ṣémù dórí Ábúrámù (10-32)

        • Ìdílé Térà (27)

        • Ábúrámù kúrò ní Úrì (31)

Jẹ́nẹ́sísì 11:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “irú àwọn ọ̀rọ̀ kan náà.”

Jẹ́nẹ́sísì 11:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 10:9, 10; Da 1:2

Jẹ́nẹ́sísì 11:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/2013, ojú ìwé 11

    7/1/2012, ojú ìwé 11

Jẹ́nẹ́sísì 11:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 9:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/1998, ojú ìwé 24-25

    12/1/1991, ojú ìwé 10

Jẹ́nẹ́sísì 11:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 3/2020, ojú ìwé 2

Jẹ́nẹ́sísì 11:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 11:1

Jẹ́nẹ́sísì 11:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 1:26

Jẹ́nẹ́sísì 11:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 32:8

Jẹ́nẹ́sísì 11:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ó túmọ̀ sí “Ìdàrú.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 50:1

Jẹ́nẹ́sísì 11:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 6:10; Lk 3:23, 36
  • +Jẹ 10:22; 1Kr 1:17

Jẹ́nẹ́sísì 11:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 10:21

Jẹ́nẹ́sísì 11:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 10:24; 1Kr 1:18; Lk 3:23, 35

Jẹ́nẹ́sísì 11:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 10:21; 1Kr 1:18

Jẹ́nẹ́sísì 11:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 10:25; 1Kr 1:19

Jẹ́nẹ́sísì 11:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Lk 3:23, 35

Jẹ́nẹ́sísì 11:24

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 11:32; Lk 3:23, 34

Jẹ́nẹ́sísì 11:26

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 12:7; 15:1, 6; 17:5; Jem 2:23
  • +Joṣ 24:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    7/15/1994, ojú ìwé 30

Jẹ́nẹ́sísì 11:27

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 12:4; 19:1; 2Pe 2:7

Jẹ́nẹ́sísì 11:28

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 15:7; Ne 9:7
  • +Iṣe 7:4

Jẹ́nẹ́sísì 11:29

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 12:11; 17:15; 20:12, 13; 1Pe 3:6
  • +Jẹ 22:20; 24:15

Jẹ́nẹ́sísì 11:30

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 16:1, 2; Ro 4:19; Heb 11:11

Jẹ́nẹ́sísì 11:31

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 11:27, 28
  • +Jẹ 10:19
  • +Jẹ 12:4; 27:42, 43; Iṣe 7:2, 4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde),

    No. 3 2017 ojú ìwé 14

    Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ, ojú ìwé 28

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2006, ojú ìwé 15

    8/15/2001, ojú ìwé 14-15, 16-17

Àwọn míì

Jẹ́n. 11:2Jẹ 10:9, 10; Da 1:2
Jẹ́n. 11:4Jẹ 9:1
Jẹ́n. 11:6Jẹ 11:1
Jẹ́n. 11:7Jẹ 1:26
Jẹ́n. 11:8Di 32:8
Jẹ́n. 11:9Jer 50:1
Jẹ́n. 11:10Jẹ 6:10; Lk 3:23, 36
Jẹ́n. 11:10Jẹ 10:22; 1Kr 1:17
Jẹ́n. 11:11Jẹ 10:21
Jẹ́n. 11:12Jẹ 10:24; 1Kr 1:18; Lk 3:23, 35
Jẹ́n. 11:14Jẹ 10:21; 1Kr 1:18
Jẹ́n. 11:16Jẹ 10:25; 1Kr 1:19
Jẹ́n. 11:18Lk 3:23, 35
Jẹ́n. 11:24Jẹ 11:32; Lk 3:23, 34
Jẹ́n. 11:26Jẹ 12:7; 15:1, 6; 17:5; Jem 2:23
Jẹ́n. 11:26Joṣ 24:2
Jẹ́n. 11:27Jẹ 12:4; 19:1; 2Pe 2:7
Jẹ́n. 11:28Jẹ 15:7; Ne 9:7
Jẹ́n. 11:28Iṣe 7:4
Jẹ́n. 11:29Jẹ 12:11; 17:15; 20:12, 13; 1Pe 3:6
Jẹ́n. 11:29Jẹ 22:20; 24:15
Jẹ́n. 11:30Jẹ 16:1, 2; Ro 4:19; Heb 11:11
Jẹ́n. 11:31Jẹ 11:27, 28
Jẹ́n. 11:31Jẹ 10:19
Jẹ́n. 11:31Jẹ 12:4; 27:42, 43; Iṣe 7:2, 4
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
  • 26
  • 27
  • 28
  • 29
  • 30
  • 31
  • 32
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Jẹ́nẹ́sísì 11:1-32

Jẹ́nẹ́sísì

11 Èdè kan ni gbogbo ayé ń sọ, wọ́n sì ń lo àwọn ọ̀rọ̀ kan náà.* 2 Bí wọ́n ṣe ń rìnrìn àjò lọ sí apá ìlà oòrùn, wọ́n rí pẹ̀tẹ́lẹ̀ kan ní ilẹ̀ Ṣínárì,+ wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í gbé ibẹ̀. 3 Wọ́n wá sọ fún ara wọn pé: “Ó yá! Ẹ jẹ́ ká mọ bíríkì, ká fi sínú iná.” Torí náà, wọ́n lo bíríkì dípò òkúta, wọ́n sì fi ọ̀dà bítúmẹ́nì ṣe àpòrọ́. 4 Wọ́n wá sọ pé: “Ó yá! Ẹ jẹ́ ká kọ́ ìlú kan fún ara wa, ká kọ́ ilé gogoro tó ga dé ọ̀run, ká mú kí orúkọ wa lókìkí, ká má bàa tú ká sí gbogbo ayé.”+

5 Ni Jèhófà bá lọ wo ìlú náà àti ilé gogoro tí àwọn ọmọ èèyàn kọ́. 6 Jèhófà sì sọ pé: “Wò ó! Èèyàn kan ni wọ́n, èdè kan+ ni wọ́n ń sọ, ohun tí wọ́n sì dáwọ́ lé nìyí. Kò ní sí ohun tí wọ́n ní lọ́kàn tí kò ní ṣeé ṣe fún wọn. 7 Wá! Jẹ́ ká+ lọ síbẹ̀ ká sì da èdè wọn rú, kí wọ́n má bàa gbọ́ èdè ara wọn mọ́.” 8 Torí náà, Jèhófà tú wọn ká láti ibẹ̀ lọ sí gbogbo ayé,+ kẹ̀rẹ̀kẹ̀rẹ̀, wọ́n fi ìlú tí wọ́n ń kọ́ sílẹ̀. 9 Ìdí nìyẹn tí wọ́n fi ń pe ibẹ̀ ní Bábélì,*+ torí ibẹ̀ ni Jèhófà ti da èdè gbogbo ayé rú, ibẹ̀ sì ni Jèhófà ti tú wọn ká sí gbogbo ayé.

10 Ìtàn Ṣémù+ nìyí.

Ẹni ọgọ́rùn-ún (100) ọdún ni Ṣémù nígbà tó bí Ápákíṣádì+ ní ọdún kejì lẹ́yìn Ìkún Omi. 11 Lẹ́yìn tó bí Ápákíṣádì, Ṣémù tún lo ọgọ́rùn-ún márùn-ún (500) ọdún. Ó sì bí àwọn ọmọ lọ́kùnrin àti lóbìnrin.+

12 Ápákíṣádì pé ẹni ọdún márùndínlógójì (35), ó wá bí Ṣélà.+ 13 Lẹ́yìn tó bí Ṣélà, Ápákíṣádì tún lo ọgọ́rùn-ún mẹ́rin ọdún ó lé mẹ́ta (403). Ó sì bí àwọn ọmọ lọ́kùnrin àti lóbìnrin.

14 Ṣélà pé ẹni ọgbọ̀n (30) ọdún, ó wá bí Ébérì.+ 15 Lẹ́yìn tó bí Ébérì, Ṣélà tún lo ọgọ́rùn-ún mẹ́rin ọdún ó lé mẹ́ta (403). Ó sì bí àwọn ọmọ lọ́kùnrin àti lóbìnrin.

16 Ébérì pé ẹni ọdún mẹ́rìnlélọ́gbọ̀n (34), ó wá bí Pélégì.+ 17 Lẹ́yìn tó bí Pélégì, Ébérì tún lo ọgọ́rùn-ún mẹ́rin ó lé ọgbọ̀n (430) ọdún. Ó sì bí àwọn ọmọ lọ́kùnrin àti lóbìnrin.

18 Pélégì pé ẹni ọgbọ̀n (30) ọdún, ó wá bí Réù.+ 19 Lẹ́yìn tó bí Réù, Pélégì tún lo igba ọdún ó lé mẹ́sàn-án (209). Ó sì bí àwọn ọmọ lọ́kùnrin àti lóbìnrin.

20 Réù pé ẹni ọdún méjìlélọ́gbọ̀n (32), ó wá bí Sérúgù. 21 Lẹ́yìn tó bí Sérúgù, Réù tún lo igba ọdún ó lé méje (207). Ó sì bí àwọn ọmọ lọ́kùnrin àti lóbìnrin.

22 Sérúgù pé ẹni ọgbọ̀n (30) ọdún, ó wá bí Náhórì. 23 Lẹ́yìn tó bí Náhórì, Sérúgù tún lo igba (200) ọdún. Ó sì bí àwọn ọmọ lọ́kùnrin àti lóbìnrin.

24 Náhórì pé ẹni ọdún mọ́kàndínlọ́gbọ̀n (29), ó wá bí Térà.+ 25 Lẹ́yìn tó bí Térà, Náhórì tún lo ọdún mọ́kàndínlọ́gọ́fà (119). Ó sì bí àwọn ọmọ lọ́kùnrin àti lóbìnrin.

26 Térà pé ẹni àádọ́rin (70) ọdún, ó sì bí Ábúrámù,+ Náhórì+ àti Háránì.

27 Ìtàn Térà nìyí.

Térà bí Ábúrámù, Náhórì àti Háránì; Háránì sì bí Lọ́ọ̀tì.+ 28 Háránì kú nígbà tí Térà bàbá rẹ̀ ṣì wà láàyè, ní ilẹ̀ tí wọ́n ti bí i, ní Úrì+ ti àwọn ará Kálídíà.+ 29 Ábúrámù àti Náhórì fẹ́ ìyàwó. Orúkọ ìyàwó Ábúrámù ni Sáráì,+ orúkọ ìyàwó Náhórì sì ni Mílíkà,+ ọmọbìnrin Háránì, bàbá Mílíkà àti Ísíkà. 30 Àmọ́ àgàn+ ni Sáráì; kò ní ọmọ kankan.

31 Térà wá mú Ábúrámù ọmọ rẹ̀ àti Lọ́ọ̀tì tó jẹ́ ọmọ ọmọ rẹ̀,+ ọmọ Háránì, ó sì mú Sáráì, ìyàwó Ábúrámù ọmọ rẹ̀, wọ́n sì tẹ̀ lé e nígbà tó kúrò ní Úrì ti àwọn ará Kálídíà láti lọ sí ilẹ̀ Kénáánì.+ Nígbà tó yá, wọ́n dé Háránì,+ wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í gbé ibẹ̀. 32 Gbogbo ọjọ́ ayé Térà jẹ́ igba ọdún ó lé márùn-ún (205). Térà wá kú ní Háránì.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́