ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Kọ́ríńtì 16
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 1 Kọ́ríńtì

      • Wọ́n kó nǹkan jọ fún àwọn Kristẹni tó wà ní Jerúsálẹ́mù (1-4)

      • Ètò ìrìn àjò Pọ́ọ̀lù (5-9)

      • Ó ṣètò bí Tímótì àti Àpólò ṣe máa bẹ àwọn ará wò (10-12)

      • Ọ̀rọ̀ ìyànjú àti ìkíni (13-24)

1 Kọ́ríńtì 16:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 24:17; Ro 15:26; 2Kọ 8:3, 4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/1/1998, ojú ìwé 24

1 Kọ́ríńtì 16:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 55

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/2013, ojú ìwé 14

    7/15/2008, ojú ìwé 28

    12/1/2002, ojú ìwé 5

    11/1/2002, ojú ìwé 26-30

    11/1/1998, ojú ìwé 24

    12/1/1994, ojú ìwé 17

    1/15/1992, ojú ìwé 17

    4/15/1991, ojú ìwé 27

    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba,

    1/2002, ojú ìwé 7

1 Kọ́ríńtì 16:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kọ 8:19

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/1998, ojú ìwé 7

1 Kọ́ríńtì 16:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/1998, ojú ìwé 7

1 Kọ́ríńtì 16:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 19:21; 2Kọ 1:15, 16

1 Kọ́ríńtì 16:7

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àfikún A5.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 20:2

1 Kọ́ríńtì 16:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 19:1

1 Kọ́ríńtì 16:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 19:10, 11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/2008, ojú ìwé 18

1 Kọ́ríńtì 16:10

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àfikún A5.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 16:1, 2
  • +Flp 2:19, 20

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    5/15/2009, ojú ìwé 15

1 Kọ́ríńtì 16:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 18:24, 25

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    10/1/1996, ojú ìwé 22

1 Kọ́ríńtì 16:13

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ẹ jẹ́ onígboyà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Tẹ 5:6
  • +1Kọ 15:58; Flp 1:27
  • +Iṣe 4:29
  • +Ef 6:10; Kol 1:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/15/2015, ojú ìwé 13-17

    1/1/2003, ojú ìwé 18-19

    4/1/2002, ojú ìwé 15, 27-28

    Jí!,

    5/8/2000, ojú ìwé 15

    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba,

    2/2000, ojú ìwé 8

1 Kọ́ríńtì 16:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 13:4; 1Pe 4:8

1 Kọ́ríńtì 16:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Flp 2:29, 30; 1Tẹ 5:12; 1Ti 5:17

1 Kọ́ríńtì 16:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 1:16

1 Kọ́ríńtì 16:19

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 16:3, 5; Flm 2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2007, ojú ìwé 10

1 Kọ́ríńtì 16:20

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 5/2019, ojú ìwé 4-5

Àwọn míì

1 Kọ́r. 16:1Iṣe 24:17; Ro 15:26; 2Kọ 8:3, 4
1 Kọ́r. 16:32Kọ 8:19
1 Kọ́r. 16:5Iṣe 19:21; 2Kọ 1:15, 16
1 Kọ́r. 16:7Iṣe 20:2
1 Kọ́r. 16:8Iṣe 19:1
1 Kọ́r. 16:9Iṣe 19:10, 11
1 Kọ́r. 16:10Iṣe 16:1, 2
1 Kọ́r. 16:10Flp 2:19, 20
1 Kọ́r. 16:12Iṣe 18:24, 25
1 Kọ́r. 16:131Tẹ 5:6
1 Kọ́r. 16:131Kọ 15:58; Flp 1:27
1 Kọ́r. 16:13Iṣe 4:29
1 Kọ́r. 16:13Ef 6:10; Kol 1:11
1 Kọ́r. 16:141Kọ 13:4; 1Pe 4:8
1 Kọ́r. 16:16Flp 2:29, 30; 1Tẹ 5:12; 1Ti 5:17
1 Kọ́r. 16:171Kọ 1:16
1 Kọ́r. 16:19Ro 16:3, 5; Flm 2
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
1 Kọ́ríńtì 16:1-24

Ìwé Kìíní sí Àwọn Ará Kọ́ríńtì

16 Ní ti àwọn ohun tí ẹ fẹ́ kó jọ fún àwọn ẹni mímọ́,+ ẹ lè tẹ̀ lé ìlànà tí mo fún àwọn ìjọ tó wà ní Gálátíà. 2 Ní gbogbo ọjọ́ kìíní ọ̀sẹ̀, kí kálukú yín ya ohun kan sọ́tọ̀ bí agbára rẹ̀ bá ṣe tó, kó má bàa sí pé ẹ̀ ń kó nǹkan jọ nígbà tí mo bá dé. 3 Àmọ́ nígbà tí mo bá dé ọ̀dọ̀ yín, màá ní kí àwọn ọkùnrin tí ẹ fọwọ́ sí nínú àwọn lẹ́tà yín  + kó ẹ̀bùn àtọkànwá yín lọ sí Jerúsálẹ́mù. 4 Àmọ́, tí mo bá rí i pé ó yẹ kí èmi náà lọ síbẹ̀, wọ́n á bá mi lọ.

5 Ṣùgbọ́n màá wá sọ́dọ̀ yín tí mo bá ti kọjá ní Makedóníà, torí mo máa gba Makedóníà kọjá;+ 6 ó sì ṣeé ṣe kí n dúró tàbí kí n tiẹ̀ lo ìgbà òtútù pẹ̀lú yín, kí ẹ lè sìn mí dé ọ̀nà ibi tí mo bá ń lọ. 7 Torí mi ò kàn fẹ́ rí yín fẹ́rẹ́ tí mo bá ń kọjá, nítorí mo ní in lọ́kàn láti lo ìgbà díẹ̀ lọ́dọ̀ yín,+ tí Jèhófà* bá yọ̀ǹda. 8 Àmọ́ màá wà ní Éfésù+ títí di ìgbà Àjọyọ̀ Pẹ́ńtíkọ́sì, 9 nítorí ilẹ̀kùn ńlá ti ṣí sílẹ̀ fún mi láti ṣe iṣẹ́ púpọ̀,+ àmọ́ ọ̀pọ̀ alátakò ló wà.

10 Tóò, tí Tímótì+ bá dé, ẹ rí i pé kò sí ohun kankan tó ń bà á lẹ́rù láàárín yín, nítorí iṣẹ́ Jèhófà* ló ń ṣe,+ bí èmi náà ti ń ṣe. 11 Nítorí náà, kí ẹnikẹ́ni má ṣe fojú kéré rẹ̀. Ẹ yọ̀ǹda rẹ̀ kó máa lọ ní àlàáfíà, kó lè wá sọ́dọ̀ mi, torí mò ń dúró dè é pẹ̀lú àwọn ará.

12 Ní ti Àpólò+ arákùnrin wa, mo pàrọwà fún un gidigidi láti tẹ̀ lé àwọn ará wá sọ́dọ̀ yín. Àmọ́ kò tíì fẹ́ wá báyìí, ó máa wá nígbà tí àyè bá ṣí sílẹ̀ fún un.

13 Ẹ wà lójúfò,+ ẹ dúró gbọn-in nínú ìgbàgbọ́,+ ẹ ṣe bí ọkùnrin,*+ ẹ di alágbára.+ 14 Ẹ máa fi ìfẹ́ ṣe gbogbo ohun tí ẹ bá ń ṣe.+

15 Ní báyìí, mo rọ̀ yín, ẹ̀yin ará: Ẹ mọ̀ pé agbo ilé Sítéfánásì ni àkọ́so Ákáyà àti pé wọ́n ti yọ̀ǹda ara wọn láti máa ṣe ìránṣẹ́ fún àwọn ẹni mímọ́. 16 Kí ẹ̀yin náà máa tẹrí ba fún irú àwọn èèyàn bẹ́ẹ̀ àti fún gbogbo àwọn tó ń fọwọ́ sowọ́ pọ̀, tí wọ́n sì ń ṣiṣẹ́ kára.+ 17 Inú mi dùn pé Sítéfánásì+ àti Fọ́túnátù pẹ̀lú Ákáíkọ́sì wà níbí, nítorí wọ́n ń ṣe àwọn ohun tí ẹ̀ bá máa ṣe ká ní ẹ wà níbí. 18 Wọ́n ti mú ìtura bá ẹ̀mí mi àti tiyín. Nítorí náà, ẹ máa ka irú àwọn èèyàn bẹ́ẹ̀ sí.

19 Àwọn ìjọ tó wà ní Éṣíà kí yín. Ákúílà àti Pírísíkà pẹ̀lú ìjọ tó wà ní ilé wọn+ kí yín tayọ̀tayọ̀ nínú Olúwa. 20 Gbogbo àwọn ará kí yín. Ẹ fi ìfẹnukonu mímọ́ kí ara yín.

21 Ìkíni èmi Pọ́ọ̀lù nìyí, tí mo fi ọwọ́ ara mi kọ.

22 Tí ẹnikẹ́ni kò bá nífẹ̀ẹ́ Olúwa, kí ó di ẹni ègún. Ìwọ Olúwa wa, máa bọ̀! 23 Kí inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí Jésù Olúwa wà pẹ̀lú yín. 24 Kí ìfẹ́ mi wà pẹ̀lú gbogbo yín nínú Kristi Jésù.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́