ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sekaráyà 7
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Sekaráyà

      • Jèhófà dẹ́bi fún àwọn tó ń gbààwẹ̀ tí kò dénú (1-14)

        • “Ṣé torí mi lẹ ṣe gbààwẹ̀ lóòótọ́?” (5)

        • ‘Ẹ dá ẹjọ́ òdodo, kí ìfẹ́ tí ẹ ní má yẹ̀, kí ẹ sì máa ṣàánú ara yín’ (9)

Sekaráyà 7:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àfikún B15.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹsr 6:14; Sek 1:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun, ojú ìwé 1706, 1796

Sekaráyà 7:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “tu Jèhófà lójú.”

Sekaráyà 7:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “tẹ́ńpìlì.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 25:8-10; Jer 52:12-14

Sekaráyà 7:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 41:1, 2
  • +Jer 25:11; Sek 1:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    11/15/1996, ojú ìwé 5

Sekaráyà 7:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 36:15

Sekaráyà 7:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 21:3; Jer 21:12
  • +Owe 16:6; Ho 10:12; Mik 6:8

Sekaráyà 7:10

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ọmọ aláìlóbìí.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 22:22; Di 24:17; Ais 1:17
  • +Ẹk 23:9; Owe 22:22; Mal 3:5
  • +Sek 8:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ọjọ́ Jèhófà, ojú ìwé 113-114

Sekaráyà 7:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 33:10; Jer 6:10
  • +Ne 9:29
  • +2Ọb 17:13, 14; Ais 6:10; Jer 25:7

Sekaráyà 7:12

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “òkúta líle,” irú bí òkúta émérì.

  • *

    Tàbí “ìtọ́ni.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 3:7
  • +Ne 9:30; Iṣe 7:51
  • +2Kr 36:15, 16; Jer 21:5

Sekaráyà 7:13

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “ó.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 50:2
  • +Ais 1:15; Ida 3:44

Sekaráyà 7:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 28:64; Jer 5:15
  • +Le 26:22, 33; 2Kr 36:20, 21

Àwọn míì

Sek. 7:1Ẹsr 6:14; Sek 1:1
Sek. 7:32Ọb 25:8-10; Jer 52:12-14
Sek. 7:5Jer 41:1, 2
Sek. 7:5Jer 25:11; Sek 1:12
Sek. 7:72Kr 36:15
Sek. 7:9Owe 21:3; Jer 21:12
Sek. 7:9Owe 16:6; Ho 10:12; Mik 6:8
Sek. 7:10Ẹk 22:22; Di 24:17; Ais 1:17
Sek. 7:10Ẹk 23:9; Owe 22:22; Mal 3:5
Sek. 7:10Sek 8:17
Sek. 7:112Kr 33:10; Jer 6:10
Sek. 7:11Ne 9:29
Sek. 7:112Ọb 17:13, 14; Ais 6:10; Jer 25:7
Sek. 7:12Isk 3:7
Sek. 7:12Ne 9:30; Iṣe 7:51
Sek. 7:122Kr 36:15, 16; Jer 21:5
Sek. 7:13Ais 50:2
Sek. 7:13Ais 1:15; Ida 3:44
Sek. 7:14Di 28:64; Jer 5:15
Sek. 7:14Le 26:22, 33; 2Kr 36:20, 21
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Sekaráyà 7:1-14

Sekaráyà

7 Ní ọdún kẹrin tí Ọba Dáríúsì ti ń ṣàkóso, Jèhófà bá Sekaráyà+ sọ̀rọ̀ ní ọjọ́ kẹrin oṣù kẹsàn-án, ìyẹn oṣù Kísíléfì.* 2 Àwọn ará Bẹ́tẹ́lì rán Ṣárésà àti Regemu-mélékì àti àwọn èèyàn rẹ̀ kí wọ́n lè bẹ Jèhófà pé kó ṣojúure sí wọn,* 3 wọ́n ń sọ fún àwọn àlùfáà ilé* Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun àti fún àwọn wòlíì pé: “Ṣé kí n sunkún ní oṣù karùn-ún,+ kí n má sì jẹun, bí mo ti ṣe fún ọ̀pọ̀ ọdún?”

4 Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun tún bá mi sọ̀rọ̀, ó ní: 5 “Sọ fún gbogbo èèyàn ilẹ̀ náà àti àwọn àlùfáà pé, ‘Nígbà tí ẹ gbààwẹ̀, tí ẹ sì pohùn réré ẹkún ní oṣù karùn-ún àti oṣù keje+ fún àádọ́rin (70) ọdún,+ ṣé torí mi lẹ ṣe gbààwẹ̀ lóòótọ́? 6 Nígbà tí ẹ jẹ tí ẹ sì mu, ṣebí torí ara yín lẹ ṣe ń jẹ tí ẹ sì ń mu? 7 Ṣé kò yẹ kí ẹ ṣe ohun tí Jèhófà sọ nípasẹ̀ àwọn wòlíì àtijọ́,+ nígbà tí àwọn èèyàn ń gbé ní Jerúsálẹ́mù àti àwọn ìlú tó yí i ká, tí wọ́n sì wà ní àlàáfíà àti nígbà tí àwọn èèyàn ń gbé ní Négébù àti Ṣẹ́fẹ́là?’”

8 Jèhófà tún sọ fún Sekaráyà pé: 9 “Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí, ‘Ẹ dá ẹjọ́ òdodo,+ kí ìfẹ́ tí ẹ ní sí ara yín má yẹ̀,+ kí ẹ sì máa ṣàánú ara yín. 10 Ẹ má lu opó tàbí ọmọ aláìníbaba* ní jìbìtì,+ ẹ má lu àjèjì tàbí aláìní ní jìbìtì,+ ẹ má sì gbèrò ibi sí ara yín nínú ọkàn yín.’+ 11 Àmọ́ wọn ò fetí sílẹ̀,+ agídí wọn mú kí wọ́n kẹ̀yìn sí mi,+ wọ́n sì di etí wọn kí wọ́n má bàa gbọ́.+ 12 Wọ́n mú kí ọkàn wọn le bíi dáyámọ́ǹdì,*+ wọn ò sì tẹ̀ lé òfin* àti ọ̀rọ̀ tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun fi ẹ̀mí rẹ̀ sọ nípasẹ̀ àwọn wòlíì àtijọ́.+ Torí náà, inú bí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun gan-an.”+

13 “Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ pé, ‘Bí wọn ò ṣe fetí sílẹ̀ nígbà tí mo* pè wọ́n,+ bẹ́ẹ̀ náà ni mi ò ní fetí sílẹ̀ tí wọ́n bá pè.+ 14 Mo sì fi ìjì tú wọn ká sí gbogbo orílẹ̀-èdè tí wọn ò mọ̀.+ Ilẹ̀ náà di ahoro lẹ́yìn wọn, ẹnì kankan ò kọjá níbẹ̀, ẹnì kankan ò sì pa dà síbẹ̀;+ torí wọ́n ti sọ ilẹ̀ dáradára náà di ohun tó ń dẹ́rù bani.’”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́