ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Sámúẹ́lì 12
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 1 Sámúẹ́lì

      • Ọ̀rọ̀ ìdágbére Sámúẹ́lì (1-25)

        • ‘Ẹ má ṣe tẹ̀ lé àwọn ohun asán’ (21)

        • Jèhófà kò ní kọ àwọn èèyàn rẹ̀ sílẹ̀ (22)

1 Sámúẹ́lì 12:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “fetí sí ohùn yín ní ti.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Sa 8:5; 10:24; 11:14, 15

1 Sámúẹ́lì 12:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “lọ níwájú.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Sa 8:20
  • +1Sa 8:1, 3
  • +1Sa 3:19

1 Sámúẹ́lì 12:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “owó mẹ́numọ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Sa 9:16, 17; 10:1
  • +Nọ 16:15
  • +Di 16:19
  • +Ẹk 22:4; Le 6:4

1 Sámúẹ́lì 12:5

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “ẹ ò rí nǹkan kan lọ́wọ́ mi.”

1 Sámúẹ́lì 12:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 6:26

1 Sámúẹ́lì 12:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 46:6
  • +Ẹk 2:23
  • +Ẹk 3:9, 10
  • +Joṣ 11:23

1 Sámúẹ́lì 12:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 32:18, 30; Ond 2:12, 14
  • +Ond 4:2
  • +Ond 10:7; 13:1
  • +Ond 3:12

1 Sámúẹ́lì 12:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ond 2:18; 3:9
  • +Ond 10:10, 15
  • +Ond 3:7
  • +Ond 2:13

1 Sámúẹ́lì 12:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ond 6:32
  • +Ond 11:1
  • +Heb 11:32
  • +Le 26:6

1 Sámúẹ́lì 12:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Sa 11:1
  • +1Sa 8:5, 19
  • +Ond 8:23; 1Sa 8:7; Ais 33:22

1 Sámúẹ́lì 12:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Sa 9:16, 17; 10:24

1 Sámúẹ́lì 12:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 10:12; 17:19
  • +Joṣ 24:14
  • +Di 13:4; 28:2

1 Sámúẹ́lì 12:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 26:14, 17; Di 28:15; Joṣ 24:20

1 Sámúẹ́lì 12:17

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “wíìtì.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Sa 8:7; Ho 13:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ, ojú ìwé 59

    Ilé Ìṣọ́,

    10/1/2010, ojú ìwé 14

1 Sámúẹ́lì 12:18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ, ojú ìwé 66

    Ilé Ìṣọ́,

    10/1/2010, ojú ìwé 18

1 Sámúẹ́lì 12:19

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Sa 7:5; 12:23

1 Sámúẹ́lì 12:20

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 31:29; Joṣ 23:6; 1Sa 12:15
  • +Di 6:5

1 Sámúẹ́lì 12:21

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “òtúbáńtẹ́.”

  • *

    Tàbí “òtúbáńtẹ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 32:21; Jer 2:11
  • +Sm 115:4, 5; Jer 16:19

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/2011, ojú ìwé 13-14

1 Sámúẹ́lì 12:22

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 6:13; Sm 94:14; Ro 11:1
  • +Joṣ 7:9; Sm 23:3; 106:8; Jer 14:21; Isk 20:14
  • +Ẹk 19:5; Di 7:7

1 Sámúẹ́lì 12:23

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    6/1/2007, ojú ìwé 28-29

1 Sámúẹ́lì 12:24

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ní òtítọ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Sa 12:14; Sm 111:10; Onw 12:13
  • +Di 10:12, 21

1 Sámúẹ́lì 12:25

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joṣ 24:20
  • +Di 28:15, 36

Àwọn míì

1 Sám. 12:11Sa 8:5; 10:24; 11:14, 15
1 Sám. 12:21Sa 8:20
1 Sám. 12:21Sa 8:1, 3
1 Sám. 12:21Sa 3:19
1 Sám. 12:31Sa 9:16, 17; 10:1
1 Sám. 12:3Nọ 16:15
1 Sám. 12:3Di 16:19
1 Sám. 12:3Ẹk 22:4; Le 6:4
1 Sám. 12:6Ẹk 6:26
1 Sám. 12:8Jẹ 46:6
1 Sám. 12:8Ẹk 2:23
1 Sám. 12:8Ẹk 3:9, 10
1 Sám. 12:8Joṣ 11:23
1 Sám. 12:9Di 32:18, 30; Ond 2:12, 14
1 Sám. 12:9Ond 4:2
1 Sám. 12:9Ond 10:7; 13:1
1 Sám. 12:9Ond 3:12
1 Sám. 12:10Ond 2:18; 3:9
1 Sám. 12:10Ond 10:10, 15
1 Sám. 12:10Ond 3:7
1 Sám. 12:10Ond 2:13
1 Sám. 12:11Ond 6:32
1 Sám. 12:11Ond 11:1
1 Sám. 12:11Heb 11:32
1 Sám. 12:11Le 26:6
1 Sám. 12:121Sa 11:1
1 Sám. 12:121Sa 8:5, 19
1 Sám. 12:12Ond 8:23; 1Sa 8:7; Ais 33:22
1 Sám. 12:131Sa 9:16, 17; 10:24
1 Sám. 12:14Di 10:12; 17:19
1 Sám. 12:14Joṣ 24:14
1 Sám. 12:14Di 13:4; 28:2
1 Sám. 12:15Le 26:14, 17; Di 28:15; Joṣ 24:20
1 Sám. 12:171Sa 8:7; Ho 13:11
1 Sám. 12:191Sa 7:5; 12:23
1 Sám. 12:20Di 31:29; Joṣ 23:6; 1Sa 12:15
1 Sám. 12:20Di 6:5
1 Sám. 12:21Di 32:21; Jer 2:11
1 Sám. 12:21Sm 115:4, 5; Jer 16:19
1 Sám. 12:221Ọb 6:13; Sm 94:14; Ro 11:1
1 Sám. 12:22Joṣ 7:9; Sm 23:3; 106:8; Jer 14:21; Isk 20:14
1 Sám. 12:22Ẹk 19:5; Di 7:7
1 Sám. 12:241Sa 12:14; Sm 111:10; Onw 12:13
1 Sám. 12:24Di 10:12, 21
1 Sám. 12:25Joṣ 24:20
1 Sám. 12:25Di 28:15, 36
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
1 Sámúẹ́lì 12:1-25

Sámúẹ́lì Kìíní

12 Níkẹyìn, Sámúẹ́lì sọ fún gbogbo Ísírẹ́lì pé: “Ẹ wò ó, mo ti ṣe* gbogbo ohun tí ẹ ní kí n ṣe, mo sì ti fi ọba jẹ lé yín lórí.+ 2 Ọba tí á máa darí* yín rèé!+ Ní tèmi, mo ti darúgbó, mo sì ti hewú. Àwọn ọmọkùnrin mi wà lọ́dọ̀ yín,+ mo sì ti ń darí yín láti ìgbà èwe mi títí di òní yìí.+ 3 Èmi nìyí. Ẹ ta kò mí níwájú Jèhófà àti níwájú ẹni àmì òróró rẹ̀:+ Akọ màlúù tàbí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ ta ni mo gbà rí?+ Àbí, ta ni mo lù ní jìbìtì tàbí tí mo ni lára? Ọwọ́ ta ni mo ti gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀,* tí màá fi gbé ojú mi sẹ́gbẹ̀ẹ́?+ Tó bá wà, màá san án pa dà fún yín.”+ 4 Wọ́n fèsì pé: “O ò lù wá ní jìbìtì, o ò ni wá lára, bẹ́ẹ̀ ni o ò gba ohunkóhun lọ́wọ́ ẹnikẹ́ni.” 5 Nítorí náà, ó sọ fún wọn pé: “Jèhófà ni ẹlẹ́rìí yín, ẹni àmì òróró rẹ̀ sì ṣe ẹlẹ́rìí lónìí yìí pé ẹ kò rí nǹkan kan tí ẹ máa fẹ̀sùn rẹ̀ kàn mí.”* Wọ́n fèsì pé: “Òun ni ẹlẹ́rìí.”

6 Sámúẹ́lì bá sọ fún àwọn èèyàn náà pé: “Jèhófà tó lo Mósè àti Áárónì, tó sì mú àwọn baba ńlá yín jáde kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì+ ni ẹlẹ́rìí. 7 Ní báyìí, ẹ dúró níwájú Jèhófà, màá bá yín ṣẹjọ́ nítorí gbogbo òdodo tí Jèhófà ti ṣe fún ẹ̀yin àti àwọn baba ńlá yín.

8 “Gbàrà tí Jékọ́bù dé sí Íjíbítì,+ tí àwọn baba ńlá yín sì bẹ̀rẹ̀ sí í ké pe Jèhófà fún ìrànlọ́wọ́,+ Jèhófà rán Mósè+ àti Áárónì, kí wọ́n lè mú àwọn baba ńlá yín jáde kúrò ní Íjíbítì, kí wọ́n sì mú kí wọ́n máa gbé ibí yìí.+ 9 Àmọ́ wọ́n gbàgbé Jèhófà Ọlọ́run wọn, ó sì tà wọ́n+ sọ́wọ́ Sísérà+ olórí àwọn ọmọ ogun Hásórì àti sọ́wọ́ àwọn Filísínì+ àti sọ́wọ́ ọba Móábù,+ wọ́n sì bá wọn jà. 10 Wọ́n ké pe Jèhófà fún ìrànlọ́wọ́,+ wọ́n sọ pé, ‘A ti dẹ́ṣẹ̀,+ nítorí a ti fi Jèhófà sílẹ̀ lọ sin àwọn Báálì+ àti àwọn ère Áṣítórétì;+ ní báyìí gbà wá lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá wa, kí a lè sìn ọ́.’ 11 Ìgbà náà ni Jèhófà rán Jerubáálì+ àti Bédánì àti Jẹ́fútà+ àti Sámúẹ́lì,+ ó sì gbà yín lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá tó yí yín ká, kí ẹ bàa lè máa gbé lábẹ́ ààbò.+ 12 Nígbà tí ẹ rí i pé Náháṣì+ ọba àwọn ọmọ Ámónì ti wá gbéjà kò yín, léraléra lẹ sọ fún mi pé, ‘Àní sẹ́, a ti pinnu láti ní ọba tiwa!’+ bó tilẹ̀ jẹ́ pé Jèhófà Ọlọ́run yín ni Ọba yín.+ 13 Ọba tí ẹ fẹ́ nìyí, ẹni tí ẹ béèrè. Ẹ wò ó! Jèhófà ti fi ọba jẹ lórí yín.+ 14 Tí ẹ bá bẹ̀rù Jèhófà,+ tí ẹ sì ń sìn ín,+ tí ẹ̀ ń ṣègbọràn sí ohùn rẹ̀,+ tí ẹ kò sì ṣọ̀tẹ̀ sí àṣẹ Jèhófà, tí ẹ̀yin àti ọba tí ó jẹ lórí yín ń tẹ̀ lé Jèhófà Ọlọ́run yín, á dáa fún yín. 15 Àmọ́ tí ẹ kò bá ṣègbọràn sí ohùn Jèhófà, tí ẹ kò sì pa àṣẹ Jèhófà mọ́, ọwọ́ Jèhófà yóò le mọ́ ẹ̀yin àti àwọn bàbá yín.+ 16 Ní báyìí, ẹ dúró, kí ẹ sì rí ohun ńlá yìí tí Jèhófà máa ṣe lójú yín. 17 Òní kọ́ ni ọjọ́ ìkórè àlìkámà* ni? Màá ké pe Jèhófà kí ó sán ààrá kí ó sì rọ òjò; kí ẹ wá mọ̀, kí ẹ sì lóye pé ohun búburú ni ẹ ṣe lójú Jèhófà nígbà tí ẹ ní kí ó fún yín ní ọba.”+

18 Ni Sámúẹ́lì bá ké pe Jèhófà, Jèhófà wá sán ààrá, ó sì rọ òjò ní ọjọ́ yẹn, tí gbogbo àwọn èèyàn náà fi bẹ̀rù Jèhófà àti Sámúẹ́lì gidigidi. 19 Gbogbo àwọn èèyàn náà sì sọ fún Sámúẹ́lì pé: “Gbàdúrà sí Jèhófà Ọlọ́run rẹ nítorí àwọn ìránṣẹ́ rẹ,+ nítorí a ò fẹ́ kú, torí pé a ti fi ohun búburú míì kún gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ wa bí a ṣe ní kí ó fún wa ní ọba.”

20 Torí náà, Sámúẹ́lì sọ fún àwọn èèyàn náà pé: “Ẹ má bẹ̀rù. Ẹ kúkú ti ṣe gbogbo ohun búburú yìí ná. Ẹ má ṣáà pa dà lẹ́yìn Jèhófà,+ kí ẹ sì máa fi gbogbo ọkàn yín sin Jèhófà.+ 21 Ẹ má ṣe lọ máa tẹ̀ lé àwọn ohun asán*+ tí kò ṣàǹfààní,+ tí kò sì lè gbani, nítorí pé asán* ni wọ́n jẹ́. 22 Jèhófà kò ní kọ àwọn èèyàn rẹ̀ sílẹ̀+ nítorí orúkọ ńlá rẹ̀+ àti nítorí pé Jèhófà ti pinnu láti fi yín ṣe èèyàn rẹ̀.+ 23 Ní tèmi, kò ṣeé gbọ́ sétí pé mo ṣẹ̀ sí Jèhófà pé mi ò gbàdúrà nítorí yín, èmi yóò sì máa fún yín ní ìtọ́ni ní ọ̀nà rere àti ọ̀nà tó tọ́. 24 Àfi kí ẹ bẹ̀rù Jèhófà,+ kí ẹ sì fi gbogbo ọkàn yín sìn ín ní òdodo,* ẹ̀yin náà ẹ wo àwọn ohun ńlá tí ó ti ṣe fún yín.+ 25 Àmọ́ bí ẹ bá fi ọ̀dájú ṣe ohun búburú, a ó gbá yín lọ,+ ẹ̀yin àti ọba yín.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́