ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 12
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Àìsáyà

      • Orin ìdúpẹ́ (1-6)

        • “Jáà Jèhófà ni okun mi” (2)

Àìsáyà 12:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 30:3; Sm 30:5; 85:1; 126:1; Ais 40:2; 66:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 169

Àìsáyà 12:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    “Jáà” ni ìkékúrú Jèhófà.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 45:17
  • +Ais 26:4
  • +Sm 118:14; Ho 1:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 169-170

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    1/1/1991, ojú ìwé 11

Àìsáyà 12:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 49:10

Àìsáyà 12:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kr 16:8; Sm 105:1, 2
  • +Ẹk 15:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 170-171

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    1/1/1991, ojú ìwé 11

Àìsáyà 12:5

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “kọrin sí.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 149:3
  • +Sm 98:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 170-171

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    1/1/1991, ojú ìwé 11

Àìsáyà 12:6

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “ìwọ obìnrin,” àwọn èèyàn náà lápapọ̀ ló ń fi wé obìnrin kan.

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 170-171

Àwọn míì

Àìsá. 12:1Di 30:3; Sm 30:5; 85:1; 126:1; Ais 40:2; 66:13
Àìsá. 12:2Ais 45:17
Àìsá. 12:2Ais 26:4
Àìsá. 12:2Sm 118:14; Ho 1:7
Àìsá. 12:3Ais 49:10
Àìsá. 12:41Kr 16:8; Sm 105:1, 2
Àìsá. 12:4Ẹk 15:2
Àìsá. 12:5Sm 149:3
Àìsá. 12:5Sm 98:1
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Àìsáyà 12:1-6

Àìsáyà

12 Ní ọjọ́ yẹn, ó dájú pé o máa sọ pé:

“Mo dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ, Jèhófà,

Torí bó tiẹ̀ jẹ́ pé o bínú sí mi,

Ìbínú rẹ ti wá rọlẹ̀, o sì tù mí nínú.+

 2 Wò ó! Ọlọ́run ni ìgbàlà mi.+

Màá gbẹ́kẹ̀ lé e, ẹ̀rù ò sì ní bà mí;+

Torí Jáà* Jèhófà ni okun mi àti agbára mi,

Ó sì ti wá di ìgbàlà mi.”+

 3 Tayọ̀tayọ̀ lẹ máa fa omi

Látinú àwọn ìsun ìgbàlà.+

 4 Ní ọjọ́ yẹn, ẹ máa sọ pé:

“Ẹ fi ọpẹ́ fún Jèhófà, ẹ ké pe orúkọ rẹ̀,

Ẹ jẹ́ kí àwọn èèyàn mọ àwọn ohun tí ó ṣe!+

Ẹ kéde pé a ti gbé orúkọ rẹ̀ ga.+

 5 Ẹ kọrin ìyìn sí* Jèhófà,+ torí ó ti ṣe àwọn ohun tó yani lẹ́nu.+

Ẹ jẹ́ kí gbogbo ayé mọ èyí.

 6 Ké jáde, kí o sì kígbe ayọ̀, ìwọ* tó ń gbé ní Síónì,

Torí Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì tóbi láàárín rẹ.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́