ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sekaráyà 13
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Sekaráyà

      • Ọlọ́run yóò mú àwọn òrìṣà àtàwọn wòlíì èké kúrò (1-6)

        • Ojú yóò ti àwọn wòlíì èké (4-6)

      • Wọ́n á kọ lu olùṣọ́ àgùntàn (7-9)

        • Ọlọ́run yóò yọ́ ìdá kẹta mọ́ (9)

Sekaráyà 13:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 36:25, 29

Sekaráyà 13:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 23:13
  • +Di 13:5

Sekaráyà 13:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 13:6-9; 18:20

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/1/2007, ojú ìwé 11

Sekaráyà 13:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 1:8; Mt 3:4

Sekaráyà 13:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/2015, ojú ìwé 15-16

Sekaráyà 13:6

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “láàárín ọwọ́ rẹ yìí?” Ìyẹn, ní àyà tàbí ẹ̀yìn.

  • *

    Tàbí “àwọn tó fẹ́ràn mi.”

Sekaráyà 13:7

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àgùntàn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 34:23; Mik 5:4; Jo 10:11; Heb 13:20
  • +Ais 53:8; Da 9:26; Iṣe 3:18
  • +Mt 26:31, 55, 56; Mk 14:27, 50; Jo 16:32

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2011, ojú ìwé 13

    Ọjọ́ Jèhófà, ojú ìwé 55

Sekaráyà 13:8

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “kú.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/1/2007, ojú ìwé 11

Sekaráyà 13:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mal 3:2, 3
  • +Jer 30:22

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/1/2007, ojú ìwé 11

Àwọn míì

Sek. 13:1Isk 36:25, 29
Sek. 13:2Ẹk 23:13
Sek. 13:2Di 13:5
Sek. 13:3Di 13:6-9; 18:20
Sek. 13:42Ọb 1:8; Mt 3:4
Sek. 13:7Isk 34:23; Mik 5:4; Jo 10:11; Heb 13:20
Sek. 13:7Ais 53:8; Da 9:26; Iṣe 3:18
Sek. 13:7Mt 26:31, 55, 56; Mk 14:27, 50; Jo 16:32
Sek. 13:9Mal 3:2, 3
Sek. 13:9Jer 30:22
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Sekaráyà 13:1-9

Sekaráyà

13 “Ní ọjọ́ yẹn, wọn yóò gbẹ́ kànga kan fún ilé Dáfídì àti fún àwọn tó ń gbé Jerúsálẹ́mù láti wẹ ẹ̀ṣẹ̀ àti èérí wọn mọ́.+

2 Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ pé, “Ní ọjọ́ yẹn, èmi yóò pa orúkọ àwọn òrìṣà rẹ́ ní ilẹ̀ náà,+ wọn ò sì ní rántí wọn mọ́; èmi yóò sì mú àwọn wòlíì+ àti ẹ̀mí àìmọ́ kúrò ní ilẹ̀ náà. 3 Tí ọkùnrin kan bá tún ń sọ tẹ́lẹ̀, bàbá àti ìyá tó bí i yóò sọ fún un pé, ‘O ti fi orúkọ Jèhófà parọ́, o máa kú ni!’ Bàbá àti ìyá tó bí i yóò sì gún un pa torí pé ó sọ àsọtẹ́lẹ̀.+

4 “Ní ọjọ́ yẹn, ojú yóò ti àwọn wòlíì nítorí ìran tí kálukú wọn ń rí nígbà tó ń sọ àsọtẹ́lẹ̀; wọn ò sì ní wọ aṣọ onírun+ mọ́ láti tan àwọn èèyàn jẹ. 5 Yóò sì sọ pé, ‘Èmi kì í ṣe wòlíì. Àgbẹ̀ ni mí, torí ọkùnrin kan rà mí láti kékeré.’ 6 Tí ẹnì kan bá sì bi í pé, ‘Ọgbẹ́ wo ló wà lára rẹ yìí?’* yóò dáhùn pé, ‘Ilé àwọn ọ̀rẹ́ mi* ni mo ti fara gba ọgbẹ́.’”

 7 Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ pé, “Ìwọ idà, dìde sí olùṣọ́ àgùntàn mi,+

Sí ọkùnrin tó jẹ́ ọ̀rẹ́ mi.

Kọ lu olùṣọ́ àgùntàn,+ kí agbo* sì tú ká;+

Èmi yóò sì yí ọwọ́ mi pa dà sí àwọn tí kò já mọ́ nǹkan kan.”

 8 Jèhófà sọ pé, “Ní gbogbo ilẹ̀ náà,

Ìdá méjì nínú rẹ̀ yóò pa run, yóò sì ṣègbé;*

Ìdá kẹta yóò sì ṣẹ́ kù síbẹ̀.

 9 Èmi yóò fi ìdá kẹta sínú iná;

Èmi yóò yọ́ wọn mọ́ bí wọ́n ṣe ń yọ́ fàdákà mọ́,

Èmi yóò sì yẹ̀ wọ́n wò bí wọ́n ṣe ń yẹ wúrà wò.+

Wọ́n á ké pe orúkọ mi,

Èmi yóò sì dá wọn lóhùn.

Màá sọ pé, ‘Èèyàn mi ni wọ́n,’+

Wọ́n á sì sọ pé, ‘Jèhófà ni Ọlọ́run wa.’”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́