ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 4
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Àìsáyà

      • Obìnrin méje máa di ọkùnrin kan mú (1)

      • Ohun tí Jèhófà mú kó rú jáde máa ní ògo (2-6)

Àìsáyà 4:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ìyẹn, ìtìjú tó máa ń bá àwọn tí kò lọ́kọ àtàwọn tí kò bímọ.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 3:25
  • +Jẹ 30:22, 23; Lk 1:24, 25

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 60

Àìsáyà 4:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 30:23; Joẹ 3:18; Sek 9:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 62-66

Àìsáyà 4:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 32:32, 33

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 67-69

Àìsáyà 4:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “ìgbẹ́.”

  • *

    Tàbí “ìmúkúrò.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 36:25
  • +Isk 22:20-22

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 69-70

Àìsáyà 4:5

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àwọsánmà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 13:21; Nọ 9:15; Sek 2:4, 5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 69, 70-71

Àìsáyà 4:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 121:5
  • +Ais 25:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 71-72

Àwọn míì

Àìsá. 4:1Ais 3:25
Àìsá. 4:1Jẹ 30:22, 23; Lk 1:24, 25
Àìsá. 4:2Ais 30:23; Joẹ 3:18; Sek 9:17
Àìsá. 4:3Ẹk 32:32, 33
Àìsá. 4:4Isk 36:25
Àìsá. 4:4Isk 22:20-22
Àìsá. 4:5Ẹk 13:21; Nọ 9:15; Sek 2:4, 5
Àìsá. 4:6Sm 121:5
Àìsá. 4:6Ais 25:4
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Àìsáyà 4:1-6

Àìsáyà

4 Obìnrin méje á di ọkùnrin kan mú ní ọjọ́ yẹn,+ wọ́n á sọ pé:

“Oúnjẹ tiwa ni a ó máa jẹ,

Aṣọ wa ni a ó sì máa wọ̀;

Ṣáà jẹ́ kí wọ́n máa fi orúkọ rẹ pè wá,

Láti mú ìtìjú* wa kúrò.”+

2 Ní ọjọ́ yẹn, ohun tí Jèhófà mú kó rú jáde máa ga lọ́lá, ògo rẹ̀ sì máa yọ, èso ilẹ̀ náà máa jẹ́ ohun àmúyangàn àti ẹwà fún àwọn tó bá yè bọ́ ní Ísírẹ́lì.+ 3 A máa pe ẹnikẹ́ni tó bá ṣẹ́ kù ní Síónì àti Jerúsálẹ́mù ní mímọ́, gbogbo àwọn tó wà ní Jerúsálẹ́mù tí a kọ sílẹ̀ pé kí wọ́n wà láàyè.+

4 Nígbà tí Jèhófà bá fọ ẹ̀gbin* àwọn ọmọbìnrin Síónì kúrò,+ tó sì fi ẹ̀mí ìdájọ́ àti ẹ̀mí tó ń jó* ṣan ìtàjẹ̀sílẹ̀ Jerúsálẹ́mù kúrò láàárín rẹ̀,+ 5 ní ọ̀sán, Jèhófà tún máa mú kí ìkùukùu* àti èéfín wà lórí gbogbo ibi tí Òkè Síónì wà àti lórí ibi tí wọ́n máa ń pé jọ sí níbẹ̀, ó sì máa mú kí iná tó mọ́lẹ̀, tó ń jó lala wà níbẹ̀ ní òru;+ torí pé ààbò máa wà lórí gbogbo ògo náà. 6 Ní ọ̀sán, àtíbàbà kan máa ṣíji bò wọ́n lọ́wọ́ ooru,+ ó máa jẹ́ ibi ààbò, ó sì máa dáàbò bò wọ́n lọ́wọ́ ìjì àti òjò.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́