Ojú ìwé 2
Ṣíṣe Ayédèrú Nǹkan Ìṣòro Gbogbo Àgbáyé 3-10
Kì í ṣe kìkì owó onípépà nìkan ló kàn, ṣùgbọ́n ó kan àwọn sọ̀wédowó, ìwé ìrajà àwìn, àwọn aṣọ òtútù, aago ọwọ́, àwọn àwòrán kíkùn, àwọn ohun èèlò ọkọ̀ òfuurufú —bí ó bá ti ṣọ̀wọ́n lóde, tí ó sì níye lórí, fura, nítorí ẹnì kan níbì kan yóò gbìyànjú láti ṣe ayédèrú rẹ̀.
Ọlọrun Jẹ́ Kí A Rí Òun 11
Wọ́n ń wá Ọlọrun nínú ọ̀pọ̀ ṣọ́ọ̀ṣì, àmọ́, wọ́n rí i nígbà tí wọ́n wo ibi tí a kìlọ̀ fún wọn kí wọ́n má wò.
Ìwọ Yóò Ha Fẹ́ Láti Wo Ṣèbé? 16
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ nǹkan fífani mọ́ra ni ìwọ yóò kọ́, àmọ́, a dábàá pé kí o wò ó lókèèrè—olóró ni.
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
A. N. Jagannatha Rao, Trustee, Madras Snake Park Trust