Ojú ìwé 2
Ìsìn Ha Já Mọ́ Nǹkan Kan Mọ́ Bí? 3-11
Ó dà bí ẹni pé ìwọ̀ oòrùn Europe ń pàdánù ìgbàgbọ́ “Kristian” tí ó ní. Kí ló fa ìdágunlá náà? Èyí ha jẹ́ ìkófìrí ìlọsílẹ̀ kan náà tí yóò ṣẹlẹ̀ ní àwọn àgbáálá ilẹ̀ míràn bí?
Bí O Ṣe Lè Ra Àlòkù Ọkọ̀ 16
Èyí yóò jẹ́ kí o mọ̀ bóyá kí o ra àlòkù ọkọ̀ kan.
Àwọn Kristian Tòótọ́ Ha Lè Retí Ààbò Àtọ̀runwá Bí? 26
Èé ṣe tí àwọn kan fi ń kú níbi tí wọ́n ti ń ṣe ìfẹ́ inú Ọlọrun, tí àwọn mìíràn tí wọ́n wà nínú ipò líléwu sì ń là á?