Ojú ìwé 2
Nígbà Tí Ogun Kì Yóò Sí Mọ́ 3-11
Ó jọ pé ìrètí fún àlàáfíà àgbáyé kò dájú. Láìka àìnírètí tí ọ̀pọ̀ ènìyàn ní sí, èé ṣe tí a fi lè ní ìgbẹ́kẹ̀lé pé ayé kan láìsí ogun ti sún mọ́lé?
Ìgbàgbọ́ Nínú Ọlọrun Ṣàkóso Mi ní Ilẹ̀ Kọ́múníìsì 12
Báwo ni ó ṣe rí láti jẹ́ Kristian tòótọ́ lábẹ́ ìṣàkóso Kọ́múníìsì ní Czechoslovakia? Ìwọ yóò gbádùn ìrírí ohun tí ó ṣẹlẹ̀ gan-an yìí.
Àrùn AIDS ní Áfíríkà—Báwo Ni Kirisẹ́ńdọ̀mù Ṣe Jẹ̀bi Rẹ̀ Tó? 19
Àrùn AIDS ti ran ilẹ̀ Áfíríkà pátápátá lọ́nà tí ó ṣàrà ọ̀tọ̀. Ẹ̀bi wo ni àwọn ṣọ́ọ̀ṣì ní lórí èyí?
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Òkè èèpo iwájú ìwé: Fọ́tò U.S. National Archives.
Apá ọ̀tún òkè èèpo iwájú ìwé: Fọ́tò WHO láti ọwọ́ W. Cutting.
Apá ọ̀tún òkè èèpo ẹ̀yìn ìwé: Fọ́tò USAF.