Ojú ìwé 2
Ìbàjẹ́ Tí Ohun Ìrìnnà Ń Ṣe Kí Ni Ojútùú Rẹ̀? 3-9
Àwọn kán sọ pé, ẹ palẹ̀ ohun ìrìnnà mọ́ láti dín ìṣèbàjẹ́ kù. Àmọ́ ọ̀pọ̀ jù lọ fara mọ́ ojútùú jáwé-o-máà-húgbò. Ojútùú kankán ha ṣeé rí bí?
Ayẹyẹ Carnival—Ó Tọ́ Tàbí Kò Tọ́? 14
Irú ayẹyẹ bẹ́ẹ̀ ha wà fún àwọn Kristian bí? Kí ni Bibeli sọ?
Kíkojú Ìkọlù Ìpayà 20
Irú ìkọlù bẹ́ẹ̀ lè jẹ́ orísun ìdàníyàn jíjinlẹ̀ àti ìsoríkọ́. Báwo ni a ṣe lè kápá wọn?
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Victorian Pictorial Borders/ Dover Publications, Inc.