Ojú ìwé 2
Àwọn Amerind Kí Ni Ìrètí Wọn fún Ọjọ́ Ọ̀la? 3-16
Fún ọ̀pọ̀ ẹ̀wádún, àwọn fíìmù tí a ṣe ní Hollywood ń ṣàgbéjáde àfinúrò ìjàkadì láàárín àwọn adamàlúù àti àwọn ará India. Kí ni ojúlówó ìtàn àwọn Ọmọ Ìbílẹ̀ America? Kí ni ìrèti wọn fún ọjọ́ ọ̀la?
Àwùjọ Àlùfáà Ọ́tọ́dọ́ọ̀sì Ha Wà Lójúfò Bí? 19
Àwùjọ àlùfáà Ọ́tọ́dọ́ọ̀sì ilẹ̀ Gíríìsì ṣayẹyẹ “Ọdún Àpókálíìsì” ní 1995. Àwọn ìgbòkègbodò ayẹyẹ náà fi ìyapa hàn láàárín wọn.
Pompeii—Ibi Tí Ohunkóhun Kò Yí Padà 22
Àwárí Pompeii lábẹ́ òkìtì eérú pèsè ojú ìwòye fífani lọ́kàn mọ́ra nípa ọ̀nà ìgbésí ayé ilẹ̀ Róòmù ìgbàanì.
[Àwọn àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Fọ́tò: Garo Nalbandian
Ẹ̀yìn ìwé: Iṣẹ́ ọnà tí a gbé karí fọ́tò tí Edward S. Curtis yà
Àwòrán àfimọ̀ fún ojú ìwé 2, 4, 7, àti 12: Ojú ará Íńdíà: D. F. Barry Photograph, Thomas M. Heski Collection; ará Íńdíà tí ń jó: Men: A Pictorial Archive from Nineteenth-Century Sources/Dover Publications, Inc.; àwọn àgọ́: Leslie’s; ìrísí onígun mẹ́rin: Decorative Art; àwọn ìrísí olóbìírípo: Authentic Indian Designs