Ojú ìwé 2
Ṣé Àwa Ni A Óò Jíhìn fún Ohun Tí A Bá Ṣe? 3-10
Lónìí, a máa ń ní ìtẹ̀sí láti dá ìwà tí kò ṣètẹ́wọ́gbà láre pẹ̀lú ọ̀rọ̀ bíi, “Kì í ṣe ẹ̀bi mi!” Àwọn púpọ̀ tún wà tí wọ́n ń jiyàn pé apilẹ̀ àbùdá máa ń sún wa sí ọ̀nà ìgbésí ayé tí kò bójú mu, pé a wulẹ̀ ń tipa bẹ́ẹ̀ ṣe ohun tí ń wá lọ́nà àdánidá.
Fọgbọ́n Lo Oògùn 11
Abájọ tí àwọn ará Áfíríkà fi ní ìgbàgbọ́ púpọ̀ nínu oògùn. Abẹ́rẹ́ àjẹsára ti dín iye àwọn tí ikú ń pa kù gidigidi láàárín wọn.
Coral—Ewu Ń Wu Ú, Ó sì Ń Kú 14
Ó lẹ́wà gidigidi gan-an! Kí ni a lè ṣe láti dáàbò bò ó?
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Fiji Visitors Bureau