Ojú ìwé 2
Ìjọba Ha Lè Fòpin sí Ìwà Ọ̀daràn Bí? 3-11
Ìwà ọ̀daràn ha tí ì nípa búburú lórí ìwọ tàbí àwọn olólùfẹ́ rẹ rí bí? Àní, bí kò bá tilẹ̀ tí ì ṣe bẹ́ẹ̀, inú rẹ yóò dùn láti mọ̀ pé ìjọba yóò fòpin sí ìwà ọ̀daràn láìpẹ́. Ṣúgbọ́n báwo ni? Ìjọba wo sì ni?
Ẹlẹgẹ́ Arìnrìn Àjò Tí Kì Í Káàárẹ̀ 15
Ẹ̀dá rírẹwà ni àwọn labalábá. Oríṣi kan máà ń ṣí kiri la ẹgbẹẹgbẹ̀rún kìlómítà já.
Àrùn Arunmọléegun—Ìmọ̀ Ni Ààbò Dídára Jù Lọ 22
Ta ni ó ń ní in? Kí ni a lè ṣe nípa rẹ̀?
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Parks Canada/J. N. Flynn
Ilé aborí-ṣóńṣó-bìdí-rẹ̀kẹ̀tẹ̀ ní ẹ̀yìn ìwé àti ojú ìwé 2: Fọ́tò U.S. National Archives