Ojú ìwé 2
Oúnjẹ Rẹ—Ìdí Tí Ó Fi Yẹ Kí O Ṣàníyàn 3-13
Àwọn ewu wo ni sísanrajù ní lórí ìlera? Báwo ni oúnjẹ rẹ ṣe kan ìṣeéṣe láti ní àrùn ọkàn àyà? Àǹfààní wo ni oúnjẹ afáralókun ní?
Àwọn Ohun Iyebíye Etídò 16
Bí wọ́n ṣe ń gbéra káàkiri lófuurufú ń fani lọ́kan mọ́ra. Mọ̀ nípa ìdí tí àwọn onímọ̀ ẹ̀rọ ìṣiṣẹ́ ọkọ̀ òfuurufú fi ń kọ́ nípa bí wọ́n ṣe ń fò.
Wíwá Tí A Wá Àìṣègbè Kiri 19
Ohun tí tọkọtaya ará Mexico kan, tí inú wọn bà jẹ́ nítorí ìṣègbè nínú àwùjọ ẹ̀dá, ti kẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ nínú àwọn ohun tó ti ṣẹlẹ̀ sí wọn níbẹ̀rẹ̀ ìgbésí ayé wọn.