Page Two 2
Ta Ni Yóò Dáàbò Bo Àwọn Ẹranko Wa? 3-11
Ṣàwárí ìdí tí ẹgbẹẹgbẹ̀rún ẹranko fi forí lé ọ̀nà àkúrun. Báwo ni a ṣe lè yẹra fún èyí?
Èé Ṣe Tí Dáyámọ́ńdì Fi Gbówó Lórí Tó Bẹ́ẹ̀? 12
Báwo ni a ṣe ń ṣe àmújáde dáyámọ́ńdì oníyebíye? Ìdáhùn náà ṣèrànwọ́ láti ṣàlàyé ìdí tí ó fi gbówó lórí.
Àwọn Ọmọdé Ha Wà Láìséwu Lọ́dọ̀ Ajá Rẹ Bí? 20
Kí ni o lè ṣe láti dáàbò bo ọmọ rẹ lọ́wọ́ ajá rírorò kan? Ṣé ẹrù iṣẹ́ olówó ajá kan nìkan ni bí?
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Ìjàpá: Zoological Parks Board of NSW