Ojú ìwé 2
Párádísè kan Láìsí Wàhálà—Nígbà Wo? 3-11
Kà nípa bí párádísè kárí ayé kan tí kò ti ní sí wàhálà yóò ṣe dé láìpẹ́.
Àwọn Ogun Ìsìn—‘Ẹ̀tàn Ọlọ́rọ̀ Ìbànújẹ́’ 12
Kí ni àwọn ogun ìsìn jẹ́? Wọ́n ha ti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run wá bí?
Ìgbésí Ayé Yàtọ̀ ní Ìsàlẹ̀ Lọ́hùn-ún 16
Àwọn tí ń ṣèbẹ̀wò sí Australia rí i pé nǹkan yàtọ̀ pátápátá níbẹ̀. Èé ṣe?