Atọ́ka Fún Ìdìpọ̀ 78 Ti jí!
ÀJỌṢEPỌ̀ Ẹ̀DÁ ÈNÌYÀN
Àbójútó Ọmọ, 12/8
A Ti Tàṣejù Bọ Ìráragbaǹkan Bí? 1/22
Àwọn Ọmọ Tí Wọ́n Ní Ìṣòro Àìlèkẹ́kọ̀ọ́, 2/22
Ìbínú Nídìí Ọkọ̀ Wíwà (ìfìbínúwakọ̀), 11/22
Ìjírẹ̀ẹ́bẹ̀ Àtọkànwá (ìgbàṣọmọ), 3/8
Ìwà Ipá Tí Àwọn Obìnrin Ń Jìyà Rẹ̀, 1/8
Ìyàlẹ́nu Amúniláyọ̀ (ẹni àgbàṣọmọ), 2/22
Kíkólòlò, 11/22
Òtítọ́ Nípa Irọ́ Pípa, 2/22
Ọ̀rẹ́ Tí Kò Ṣeé Yà, 4/22
Ran Àwọn Ọmọ Rẹ Lọ́wọ́ Láti Ní Láárí, 8/8
Ṣíṣètọ́jú, 2/8
Ta Lòbí? Ta Lọmọ? 10/8
ÀWỌN ÀLÁMỌ̀RÍ ÀTI IPÒ AYÉ
Àjàkálẹ̀ Àrùn, 11/22
Àjọ OSCE—Kí Ló Jẹ́? 8/22
Ariwo, 11/8
Àṣà Ìbálòpọ̀—Ìṣarasíhùwà Tí Ń Yí Pa Dà, 6/8
Àwọn Gbájú-Ẹ̀, 9/22
Àwọn Obìnrin, 4/8
Chernobyl, 4/22
Èé Ṣe Tí Ìkórìíra Fi Pọ̀ Tó Bẹ́ẹ̀? 9/8
Ìsọdaṣálẹ̀, 2/8
Ìṣòro Omi, 8/22
Ìwà Ipá Tí Àwọn Obìnrin Ń Jìyà Rẹ̀, 1/8
Ìwà Ọ̀daràn Tí Ẹgbẹ́ Ń Ṣètò, 3/8
Ìwọra—Bó Ṣe Kàn Wá, 1/8
Kíkó Àwọn Ọmọdé Nífà Ìbálòpọ̀, 4/8
Ohun Àṣenajú, 5/22
Ohun Tí Ogun Ń Ṣe fún Àwọn Ọmọdé, 10/22
Oúnjẹ fún Gbogbo Ènìyàn—Àlá Lásán Ni Bí? 8/8
ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ
A Dá Wọn Láre ní Gíríìsì, 3/22
Àwòkọ́ṣe Láti Fara Wé, 4/22
Àwọn Adití Ń Yin Jèhófà (àwọn àpéjọpọ̀ fún àwọn adití), 4/8
Àwọn Àpéjọpọ̀ Romania, 2/22
Àwọn Ońṣẹ́ Àlàáfíà ní Ìlà Oòrùn Europe, 3/8
“Ìtànṣán Ìmọ́lẹ̀ ní Sànmánì Ojú Dúdú” (àfihàn kíní ti fídíò Stand Firm), 6/22
“Ohun Tí Adìyẹ Ń Lé Kiri Nínú Òjò” (Nàìjíríà), 5/22
Òpópónà Emmy Zehden, 1/22
Ọ̀rẹ́ Tí Kò Ṣeé Yà (A. Evaldsson), 4/22
Rọ́ṣíà, 8/22
“Wulẹ̀ La Ojú Rẹ Kí O sì Wò Ó” (àròkọ ọmọ ilé ẹ̀kọ́), 6/22
ÀWỌN ẸRANKO ÀTI OHUN Ọ̀GBÌN
Àkókò Ìrọ́gììrì Níbi Ìrugùdù Òkun Gíga (àwọn ẹyẹ lẹ́nu odò), 3/22
Àwọn Òdòdó Ń Fi Hàn Pé Ẹnì Kan Bìkítà, 3/8
Àwọn Ohun Iyebíye Etídò (àwọn lámilámi), 6/22
Àwọn Olùtànmọ́lẹ̀ Tíntìntín (àwọn ìmú-ùnmúná), 4/8
Àwọn Ọgbà, 4/8
Àwọn Ọgbà Ẹranko, 7/8
Àwọn Ọmọdé Ha Wà Láìséwu Lọ́dọ̀ Ajá Rẹ Bí? 7/8
Àwọn Wádòwádò Aládé, 10/22
Bí Kòkòrò Ṣe Ń Fò, 9/22
Dídáàbòbo Àwọn Ẹranko, 7/8
Ètò Ààbò Ojúu Títì fún Àwọn Ẹranko Igbó, 9/8
Ẹja Cod, 11/22
Ẹranko Cheetah, 9/22
Ẹyẹ Albatross 6/22
Ẹyẹ Ìwò, 1/8
Gbin Àwọn Èèhù Tìrẹ, 2/8
Ìgbà Wo Ni Kòkòrò Oyin Kì Í Ṣe Kòkòrò Oyin? 12/8
Irà Oníkoríko, 1/22
Ògbóǹkangí Olùtọ́jú Ọgbà (kòkòrò jáwéjáwé), 3/22
Òkìtì Ẹ̀dá Omi Abìlẹ̀kẹ̀, 8/8
Oorun Ẹranko, 10/8
Sísin Kòkòrò Oyin, 5/22
Yíyán Àwọn Ẹranko Ìgbẹ́, 8/8
ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ
Bíbúmọ́ni—Ewu Wo Ló Wà Níbẹ̀? 3/22
Dídánilẹ́bi, 7/22, 8/22
Dídi Ọ̀rẹ́ Ọlọ́run, 2/22
Èé Ṣe Tí Wọ́n Ń Fún Arákùnrin Ní Àfiyèsí? 10/22
Ijó Rave Ha Jẹ́ Amóríyá Aláìléwu Bí? 12/22
Kí N Jẹ́wọ́ Ẹ̀ṣẹ̀ Mi Bí? 1/22
Ojúsàájú, 11/22
Ọlọ́run Yóò Ha Máa Jẹ́ Ọ̀rẹ́ Mi Nìṣó Bí? 5/22
Ṣíṣàìsàn, 4/22, 6/22
Wíwá Owó, 9/22
ÈTÒ ỌRỌ̀ AJÉ ÀTI IṢẸ́
Iṣẹ́ Ń Sú Ọ Bí? 12/22
ÌLERA ÀTI ÌṢÈGÙN
Àjàkálẹ̀ Àrùn, 11/22
Àrùn Àìlágbára Egungun, 6/8
Àrùn Àtọ̀sí Ajá, 2/22
Àrùn RSD—Àrùn Ríronilára Kan Tí Ń Rúni Lójú, 9/8
Àṣejù Eré Ìmárale, 9/8
Àwọn Kíndìnrín, 8/8
Àwọn Ọ̀nà Tí O Lè Gbà Dáàbò Bo Ìlera, 11/22
Dídáàbòbo Ìlera Àwọn Ọmọ, 9/22
Ẹsẹ̀ Ríro, 10/8
Ibà, 7/22
Ikọ́ Ẹ̀gbẹ, 12/22
Kíkólòlò, 11/22
Mo Láyọ̀ Láti Wà Láàyè! 4/22
Oúnjẹ, 6/22
Ọgbọ́n Tí Ó Wà Nínú Títakété sí Ìbálòpọ̀ àti Ìgbéyàwó Ọkọ-Kan-Aya-Kan, 5/22
Ọ̀nà Ìgbésí Ayé Eléwu, 7/22
Ṣíṣètọ́jú, 2/8
ILẸ̀ ÀTI ÀWỌN ÈNÌYÀN
Agbára Láti Inú Òjò Dídì (Australia), 10/22
Àwọn Ará Etruria—Àdììtú Tí Ń Wà Nìṣó, 11/8
Àwọn Ìlù Áfíríkà, 7/22
Àwọn Ìró Didgeridoo (Australia), 4/22
Àwọn Kúrékùré, 12/8
Àwọn Ogun Ìsìn ní Ilẹ̀ Faransé, 4/22
Àwọn Olùtànmọ́lẹ̀ Tíntìntín ní New Zealand (àwọn ìmú-ùnmúná), 4/8
Brunost—Wàràkàṣì Aládùn Láti Norway, 7/8
Cuzco—Olú Ìlú Ìgbàanì Ti Àwọn Ará Inca, 9/8
Ebi Tẹ̀mí ní Romania, 4/22
Erékùṣù Cocos—Ìṣúra Abẹ́ Ilẹ̀ (Costa Rica), 9/22
Igi Gbígbẹ́—Iṣẹ́ Ọnà Àtayébáyé Ilẹ̀ Áfíríkà, 9/22
Ìgbésí Ayé ní Ìsàlẹ̀ Lọ́hùn-ún (Australia), 10/8
Igbó Kìjikìji Amazon, 3/22
Ilé Ìwòran Orin Aláré Nínú Igbó Kìjikìji (Brazil), 5/22
Kaba—Oríṣi Aṣọ Agbógoyọ Ilẹ̀ Áfíríkà, 9/8
Kilimanjaro—Ibi Gíga Jù Lọ ní Áfíríkà, 9/8
Kòtò Àfonífojì Ńlá, 7/22
Matera—Ìlú Ńlá Àwọn Ibùgbé Inú Hòrò (Ítálì), 7/8
Moscow, 12/22
Popocatepetl—Òkè Ayọnáyèéfín ti Mexico, 3/8
Singapore—Ọ̀ṣọ́ Iyebíye Ilẹ̀ Éṣíà Tí Wọ́n Bà Jẹ́, 6/8
Tasmania, 5/8
ÌSÌN
Àwọn Ogun Ìsìn, 10/8
Bí Bíbélì Èdè Faransé Ṣe Jìjàkadì Láti Máa Wà Nìṣó, 12/8
Ebi Tẹ̀mí ní Romania, 4/22
Gbígbẹ́jọ́ “Aládàámọ̀” Kan àti Pípa Á, 5/8
Ìjọ Kátólíìkì àti Ẹfolúṣọ̀n, 10/22
Ìsìn Ń Jagun, 4/22
Ọlọ́run—Eléèṣì Tàbí Ẹlẹ́dàá? 5/8
ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ
Etí Ọmọdé Kan (L. Lawson), 6/8
Ẹ̀kọ́ Àríkọ́gbọ́n Láti Inú Ìkòkò Ọ̀rá Kan (K. Hahn), 10/22
Fífomijé Fúnrúgbìn, Fífìdùnnú Kórè (R. Kirkup), 2/8
Ìyàlẹ́nu Amúniláyọ̀ Kan (D. Folz), 2/22
Jèhófà Mú Ipa Ọ̀nà Wa Jọ̀lọ̀ (J. Heggli), 12/8
Mo Láyọ̀ Láti Wà Láàyè! (G. Klauss), 4/22
Mo Rí Òtítọ́ Nígbẹ̀yìngbẹ́yín (E. Szanyi), 4/8
Mo Ti Rí Ọ̀pọ̀ Ọlọ́run Kí N Tó Wá Rí Ọlọ́run Tòótọ́ Náà (C. Bright), 5/22
“Nígbà Tí Èmi Bá Jẹ́ Aláìlera, Nígbà Náà Ni Mo Di Alágbára” (L. Maass), 1/22
“Oníbàárà Ní Ń Tọ̀nà” (W. Chin), 12/22
Orin, Oògùn Líle, àti Ìmutípara Ló Jàrábà Ìgbésí Ayé Mi Tẹ́lẹ̀ Rí (B. McKerchie), 1/8
Ó Sàn Ju Òkìkí Ayé Lọ (C. Pertot), 8/22
Wíwá Tí A Wá Àìṣègbè Kiri (A. Villa), 6/22
Yakuza Kan Ni Mí Tẹ́lẹ̀ (Y. Kataoka), 3/8
OJÚ ÌWÒYE BÍBÉLÌ
Èé Ṣe Tó Fi Yẹ Kí O Ṣàkóso Ìbínú Rẹ? 6/8
Ìkún Omi—Òtítọ́ Tàbí Àròsọ? 2/8
Ilẹ̀ Ayé Yóò Ha Jóná Lúúlúú Bí? 1/8
Ìmọ̀ Ìjìnlẹ̀ àti Bíbélì Ha Fohùn Ṣọ̀kan Bí? 7/8
Ipò Òṣì Ha Dá Olè Jíjà Láre Bí? 11/8
Ìṣẹ́ra-Ẹni-Níṣẹ̀ẹ́ Ha Ni Ọ̀nà Àtilọ́gbọ́n Bí? 10/8
Kí A Máa Bá Ìgbéyàwó Lọ Lẹ́yìn Ìhùwà Àìtọ́ Bí? 4/8
“Kì Í Ṣe Apá Kan Ayé,” 9/8
Ó Ha Lòdì Láti Máa Jẹ Ẹran Bí? 8/8
Ó Ha Yẹ Kí Àwọn Kristẹni Jẹ́ Ayẹrafógun Bí? 5/8
Ó Ha Yẹ Kí Àwọn Kristẹni Kórìíra Àwọn Abẹ́yà-Kannáà-Lòpọ̀? 12/8
Ó Ha Yẹ Kí Àwọn Ọmọdé Yan Ìsìn Bí? 3/8
Ọ̀KANKÒJỌ̀KAN
Àárẹ̀—Ìdẹkùn fún Àwọn Awakọ̀ Akẹ́rù, 8/8
“Àṣìṣe Méje tí Àìgbọ́n Fà Láyé,” 1/8
Àwọn Ọgbà Ohun Alààyè ti Orílẹ̀-Èdè Níbi Òkè, 11/22
Fífami Láti Inú Kùrukùru, 10/8
Ìdí Tí Dáyámọ́ńdì Fi Gbówó Lórí Tó Bẹ́ẹ̀, 7/8
Ilé Ìgbọ́únjẹ Lè Gbádùn Mọ́ni, 1/8
Ìsokọ́ra Alátagbà Internet, 7/22
Kí Ní Ń Mú Àwọn Ènìyàn Láyọ̀? 10/22
Kọfí Espresso—Ògidì Kọfí, 11/8
Ǹjẹ́ O Mọ̀? 2/8, 4/8, 6/8, 8/8, 10/8, 12/8
Ọgbà Àgbáyé, 4/8
Ọkùnrin Tó Ṣí Ayé Payá (Magellan), 11/8
Ọ̀nà Abẹ́lẹ̀, 3/22
Párádísè Kan Láìsí Wàhálà, 10/8
Ṣírò Ohun Tí Kíkó Lọ Yóò Ná Ọ! 5/8
Via Egnatia (òpópó ilẹ̀ Róòmù), 8/22
SÁYẸ́ǸSÌ
Agbára Ìgbọ́ròó—Ẹ̀bùn Tí Ó Yẹ Kí A Ṣìkẹ́, 9/22
Àwọn Kíndìnrín, 8/8
Báwo La Ṣe Déhìn-ín? 5/8
Bí Kòkòrò Ṣe Ń Fò, 9/22
“Ìbáramu Ìṣètò Àkókò Lọ́nà Kíkọyọyọ” (ọ̀rọ̀ sísọ), 9/8
Ìbí Ìràwọ̀ Nínú “Ìtẹ́” Idì Kan, 3/8
Ìlànà Photosynthesis, 1/22
Ìpìlẹ̀ Ẹfolúṣọ̀n Kò Ha Kúnjú Òṣùwọ̀n Bí? 5/8
Ìràwọ̀ Onírù Fọ́ Yángá! 1/8
“Jìbìtì Tí Ó Lókìkí Burúkú Jù Lọ Nínú Ìmọ̀ Ìjìnlẹ̀,” 7/8